Yoruba Hymn: Sunm’ọdọ wa Emmanuel – Draw nigh draw nigh Emmanuel
Sunm’ọdọ wa Emmanuel – Draw nigh, draw nigh, Emmanuel
Bible Reference:
Isaiah 59:20 (KJV) And the Redeemer shall come to Zion, and unto them that turn from transgression in Jacob, saith the LORD.
Isaiah 59 : 20 – Olurapada yio si wá si Sioni, ati sọdọ awọn ti o yipada kuro ninu irekọja ni Jakobu, ni Oluwa wi.
Sunm’ọdọ wa Emmanuel
VERSE 1
Sunm’ọdọ wa, Emmanuel,
Wa, ra Israẹli pada,
T’ o nsọfọ li oko ẹrú,
Titi Jesu y’o tun pada.
Ẹ yọ, ẹ yọ ! Emmanuel
Y’o wa s’ ọdọ wa Israeli.
VERSE 2
Wa, ọpa Alade Jesse,
K’ o gba wa l’ ọwọ ọta wa
Gba wa l’ọw’ ọrun apadi
Fun wa ni ’ṣǝgun l’ ori ’ku,
VERSE 3
Sunmọ wa, ’Wọ Ila- orun,
Ki bibo Rẹ ṣe ’tunu wa,
Tu gbogbo iṣudẹdẹ ka
M’ ẹsẹ ati egbe kuro.
VERSE 4
Wa Ọmọ ’lẹkun Dafidi,
’Lẹkun Ọrun y’o si fun Ọ;
Tun ọna ọrun ṣe fun wa,
Jọ se ọna oṣi fun wa:l.
VERSE 5
Wa Oluwa alagbara
T’ o f’ ofin fun eniyan Rẹ
Nigbani l’or’eniyan Rẹ
’Ninu ọlanla pẹl’ẹru.
Ẹ yọ, ẹ yọ ! Emmanuel
Y’o wa s’ ọdọ wa Israeli. Amin
Draw nigh, draw nigh, Emmanuel
VERSE 1
Draw nigh, draw nigh, Emmanuel,
And ransom captive Israel,
That mourns in lonely exile here
Until the Son of God appear.
Rejoice, rejoice, Emmanuel
Shall come to thee, O Israel.
VERSE 2
Draw nigh, O Jesse’s Rod, draw nigh,
To free us from the enemy;
From hell’s infernal to save,
And give us victory o’er the grave.
VERSE 3
Draw nigh, draw nigh, O Morning Star,
And bring us comfort from afar;
And banish far from us the gloom
Of sinful night and endless doom.
VERSE 4
Draw nigh, draw nigh, O David’s Key,
The heavenly gate unfolds to Thee;
Make safe the way that leads on high,
And close the path to misery.
VERSE 5
Draw nigh, draw nigh, O Lord of might,
Who to Thy tribes from Sinai’s height,
In ancient time, didst give the law
In cloud, and majesty, and awe.
Rejoice, rejoice, Emmanuel
Shall come to thee, O Israel. Amin