Yoruba Hymn: Yin Oluwa Olodumare, Ọba Ẹlẹdaa – Praise to the Lord, the Almighty

Yoruba Hymn: Yin Oluwa Olodumare, Ọba Ẹlẹdaa – Praise to the Lord, the Almighty

CAC Hymn 95: Yin Oluwa Olodumare, Ọba Ẹlẹdaa – Praise to the Lord, the Almighty

Bible Reference: 

Colossians 1:16 NKJV – For by Him all things were created that are in heaven and that are on earth, visible and invisible, whether thrones or dominions or principalities or powers. All things were created through Him and for Him.

Kol 1:16 –  Nitori ninu rẹ̀ li a ti dá ohun gbogbo, ohun ti mbẹ li ọrun, ati ohun ti mbẹ li aiye, eyiti a ri, ati eyiti a kò ri, nwọn iba ṣe itẹ́, tabi oye, tabi ijọba, tabi ọla: nipasẹ rẹ̀ li a ti dá ohun gbogbo, ati fun u:

Yin Oluwa Olodumare, Ọba Ẹlẹdaa

Yin Oluwa Olodumare, Ọba Ẹlẹdaa
Yin ọkan mi to r’On ni ‘lera ati ‘gbala rẹ 
Arakunrin,
Arabinrin sunmọ ‘hin
F’ayọ at’orin juba Rẹ 
Yin Oluwa, Ẹni t’O joba 
lor’ ohun gbogbo
To dabobo, to si gbe ọ ro labẹ iyẹ Rẹ 
O ha ri pe?
Gbogb’ ohun totọ lo ṣe 
B’O ti lana n’ipilẹsẹ.
Yin Oluwa to mbukun ‘ṣe rẹ 
to si ngbeja rẹ;
L’otitọ ire ati anu Rẹ ntọ ọ lẹyin 
‘Gbana ronu
Ohun t’Oluwa le ṣe 
Ẹni to fẹ ọ, t’O yan ọ.
Yin Oluwa! Ki gbogb’ ẹyà 
ara mi juba Rẹ 
Ki gbogbo ohun t’o l’ẹmi wa pẹlu iyin Rẹ.
Jẹki iro
Amin dun jakejado,
Layọ lao juba Re titi.
Amin.

Praise to the Lord, the Almighty

Praise to the Lord, the Almighty,
the King of creation,
O my soul, praise Him 
for He is thy health and salvation;
All ye who hear,
Brothers and sisters draw near,
Praise Him in glad adoration.
Praise to the Lord, who o'er all things so wondrously reigneth,
Shelters thee under His wings, yea, so
Gently sustaineth;
Hast thou not seen?
All that is needful hath been;
Granted in what he ordaineth.
Praise to the Lord, who doth prosper
Thy work and defend thee;
Surely His goodness and mercy here daily attend thee;
Ponder anew
What the Almighty can do,
If with His love he befriend thee.
Praise to the Lord! O let all that is in me adore Him!
All that hath life and breath, come
now with praises before Him!
Let the Amen
Sound from His people again:
Gladly for aye we adore him.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *