Yoruba Hymn: Gbe Oluwa ga pelu mi – O Magnify the Lord with me

Yoruba Hymn: Gbe Oluwa ga pelu mi – O Magnify the Lord with me

CAC Hymn 92: Gbe Oluwa ga pelu mi – O Magnify the Lord with me

Bible Reference: 

Psalm 67:3 NKJV – Let the peoples praise You, O God; Let all the peoples praise You.

Orin-Dafidi-67-vs-3_Psalms-67-vs-3 Yoruba Hymn: Gbe Oluwa ga pelu mi - O Magnify the Lord with me

Orin Dafidi 67:3 –  Jẹ ki awọn enia ki o yìn ọ, Ọlọrun; jẹ ki gbogbo enia ki o yìn ọ.

Gbe Oluwa ga pelu mi 

Gbe Oluwa ga pẹlu mi 
Ẹyin eniyan Rẹ 
Ki gbogbo ẹda alaye 
Ma yo l’oruko Rẹ 
Fun ìfẹ ti O nfihan 
Fun isimi l’ọkan wa 
Fun igbala kikun Rẹ, 
Tirẹ l’ọpẹ. 

   Ki gbogbo wa f’ọpẹ fun 
   Ki gbogbo wa f’ọpẹ fun 
   Ki gbogbo wa yin oruko
   Oluwa wa 
   Titi laelae, ani, titi laelae 
   Ki gbogbo wa f’ope fun 
   Ki gbogbo wa f’ope fun 
   Ki gbogbo wa yin oruko
   Oluwa Titi laelae. 
Ẹyin fun iwa mimọ Rẹ, 
Fun ore-ọfẹ Rẹ, 
Korin iyin fun ẹjẹ Rẹ
To fi ra wa pada 
Ifẹ lo fi wa wa ri 
Ninu ira ẹsẹ wa 
O f’ọna iye han wa 
Ẹ f’ọpẹ fun. 
Emi ‘ba l’ẹgbẹrun ahọn, 
Nko le royin na tan; 
Ifẹ Rẹ si mi pọ jọjọ, 
Ago ‘bukun mi kun, 
Ore-ọfẹ ti ki yẹ, 
Alafia bi odo 
Lat’ọdọ Olubukun; 
Ẹ f’ọpẹ fun. Amin.

O Magnify the Lord with me

O Magnify the Lord with me,
Ye people of His choice!
Let all to whom He lendeth breath
Now in His name rejoice,
For love’s blest revelation,
For rest from condemnation,
For uttermost salvation,
To Him give thanks.

 Let all …the people praise Thee,
 Let all …the people praise Thee!
 Let all …the people praise Thy name
 For ever and for evermore
 Let all …the people praise Thee
 Let all …the people praise Thee
 Let all …the people praise Thy name
For ever and for ever more.
O praise Him for His holiness,
His wisdom and His grace,
Sing praises for the precious blood
Which ransom’d all our race;
In tenderness He sought us,
From depths of sin He brought us,
The way of life then taught us,
To Him give thanks.
Had I a thousand tongues to sing,
The half could ne’er be told
Of love so rich, so full and free,
Of blessings manifold;
Of grace that faileth never,
Peace flowing as a river
From God the glorious Giver,
To Him give thanks.
 
Amen.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *