Yoruba Hymn: ‘Gbat’agbara Olorun De – When the Power of God Descended
‘Gbat’agbara Olorun De – When the Power of God Descended
Bible Reference:
Acts 1:8 (KJV) – But ye shall receive power, after that the Holy Ghost is come upon you: and ye shall be witnesses unto me both in Jerusalem, and in all Judaea, and in Samaria, and unto the uttermost part of the earth.
Ise Awọn Aposteli 1 :8 – Ṣugbọn ẹnyin ó gbà agbara, nigbati Ẹmí Mimọ́ ba bà le nyin: ẹ o si ma ṣe ẹlẹri mi ni Jerusalemu, ati ni gbogbo Judea, ati ni Samaria, ati titi de opin ilẹ aiye.
Gbat’agbara Olorun De
VERSE 1
‘Gbat’agbara Ọlọrun dé,
Li ọjọ pentikosti,
Sa if’oju s’ọna pari,
Tori wọn rí Ẹmi gba
Ran agbára, Oluwa,
Ran agbára, Oluwa,
Ran agbára, Oluwa,
Ki O sí baptisi wa
VERSE 2
Ela’han ina ba le wọn
Wọn sì wasu ọrọ na;
Ọpọlọpọ èèyàn gbagbọ
Wọn yipada s’Ọlọrun
VERSE 3
Anw’ọna fun Ẹni Mimọ
Gbogbo wa f’ohun sọkan,
Mu’leri na ṣẹ, Olúwa
Ti a ṣe nin’ọrọ Rẹ.
VERSE 4
Jọ, fi agbára Rẹ kun wa,
Fún wa ni’ bukun ta nfẹ;
Fi ogo rẹ kun ọkan wa,
Ba ti nfi gbagbọ bẹbẹ. Amin
When the Power of God Descended
VERSE 1
When the power of God descended
On the day of Pentecost,
All the days of waiting ended,
They received the Holy Ghost
Chorus
O Lord, send the power just now,
O Lord send the power just now,
O Lord send the power just now,
And baptize everyone.
VERSE 2
Tongues of flame came down upon them,
And they preached the word in power,
Listening multitudes awakened
Turned to God that very hour
VERSE 3
We are waiting Holy Spirit
We are all of one accord,
Lord fulfill just now the promise
That is given in thy Word..
VERSE 4
Fill and thrill us with Thy presence,
Grant the blessing that we need
Flood our souls with wondrous glory,
While the prayer of faith we plead.
Author: Mary Hubbert Munford
