Yoruba Hymn: Mo nduro lori ìlérí Kristi Ọba – Standing on the promises of Christ my King

Yoruba Hymn: Mo nduro lori ìlérí Kristi Ọba – Standing on the promises of Christ my King

Hymn: Mo nduro lori ìlérí Kristi Ọba – Standing on the promises of Christ my King

Bible Reference: 

2 Corinthians 1:20 NKJV – For all the promises of God in Him are Yes, and in Him Amen, to the glory of God through us. 


2 Kọrinti 01:20 – Nitoripe bi o ti wu ki ileri Ọlọrun pọ̀ to, ninu rẹ̀ ni bẹ̃ni: ati ninu rẹ̀ pẹlu ni Amin, si ogo Ọlọrun nipasẹ wa..

Mo nduro lori ìlérí Kristi Ọba

Mo nduro lori ìlérí Krist'Ọba
Ẹnití a o ma yin titi laelae
Ogo f'Ọlọrun, emi yo ma kọrin
Mo nduro lori ileri Rẹ

Emi nduro
Emi nduro lori ìlérí Oluwa
Emi nduro
Emi nduro
Mo nduro lori ìlérí Rẹ

Mo nduro le ileri ti ko le yẹ
Gbati iji 'yemeji at'ẹru ba dé
Nipa ọrọ Rẹ li emi yo ṣẹgun
Mo nduro lori ìlérí Rẹ
Ìlérí Rẹ la mi loju lati ri
Iwẹnumọ pipe ninu ẹjẹ Rẹ
Ile Rẹ sọ ọkan mi d'ominira
Mo nduro lori ìlérí Rẹ
Mo nduro le ileri Krist'Oluwa
Ifẹ lo fi so mi pọ mọ ara Rẹ
Nipa ọrọ Rẹ mo nṣẹgun lọjọ jọ
Mo nduro lori ìlérí Rẹ. 

Standing on the promises of Christ my King

Standing on the promises of Christ my King,
Through eternal ages let His praises ring,
Glory in the highest, I will shout and sing,
Standing on the promises of God.

Standing, standing,
Standing on the promises of God my Savior;
Standing, standing,
I’m standing on the promises of God.


Standing on the promises that cannot fail,
When the howling storms of doubt and fear assail,
By the living Word of God I shall prevail,
Standing on the promises of God.
Standing on the promises I now can see
Perfect, present cleansing in the blood for me;
Standing in the liberty where Christ makes free,
Standing on the promises of God.
Standing on the promises of Christ the Lord,
Bound to Him eternally by love’s strong cord,
Overcoming daily with the Spirit’s sword,
Standing on the promises of God.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *