Yoruba Hymn: Fun wa ni ‘le Kristian – God give us Christian homes

Hymn: Fun wa ni ‘le Kristian – God give us Christian homes
Bible Reference:
Luke 10:38b NKJV – Martha welcomed Him into her house.
Luku 10:38b – Marta si gbà a si ile rẹ̀.
Fun wa ni ‘le Kristian
Fun wa ni 'le Kristian
Ile ti a nkẹkọ Bibeli
Ile ti a nlepa ‘fẹ baba
'La ti 'fẹ Rẹ f‘ẹwa de l' ade
Ọlọrun Baba wa,
Fun wa n'ile Kristian.
Fun wa ni 'le Kristian
Nibiti bale jẹ olotọ
Ile t'o bọ lọwọ aṣiṣ̣e
Ile ti nyọ fun ‘fẹ at' orin
Ọlọrun Baba wa,
Fun wa ni ‘le Kristian
Fun wa ni 'le Kristian
Nibit‘ iya ile, b' ayaba
Nfihan p' ọna Rẹ lo dara ju
Ile t'a gb' Olugbala l'aye
Ọlọrun Baba wa,
Fun wa ni ‘le Kristian.
Fun wa ni 'le Kristian
Nibiti a ntọ awọn 'mọde
Lati mọ Kristi t' o fẹran wọn
Ile ti a ntanna adura
Ọlọrun Baba wa,
Fun wa ni 'le Kristian. Amin.
God give us Christian homes!
God give us Christian homes!
Homes where the Bible is loved and taught,
Homes where the Master’s will is sought,
Homes crowned with beauty Your love has wrought;
God give us Christian homes;
God give us Christian homes!
God give us Christian homes!
Homes where the father is true and strong,
Homes that are free from the blight of wrong,
Homes that are joyous with love and song;
God give us Christian homes;
God give us Christian homes!
God give us Christian homes!
Homes where the mother, in caring quest,
Strives to show others Your way is best,
Homes where the Lord is an honored guest;
God give us Christian homes;
God give us Christian homes!
God give us Christian homes!
Homes where the children are led to know
Christ in His beauty who loves them so,
Homes where the altar fires burn and glow;
God give us Christian homes;
God give us Christian homes!