Yoruba Hymn: O fun mi l’edidi Gbese nla ti mo jẹ

Yoruba Hymn: O fun mi l’edidi Gbese nla ti mo jẹ

Hymn 698 – CHRIST APOSTOLIC CHURCH HYMNAL

O fun mi l’edidi Gbese nla ti mo jẹ – He gave to me a seal

 

mf  O fun mi l’edidi

Gbese nla ti mo jẹ

B’o ti fún mi, O sí rẹrin

Pe; máṣe gbagbe mi

 

mf  O fun mi l’edidi

O san igbese na,

B’ o ti fún mi, O sí rẹrin

Wipe; ma rántí mi.

 

mf  Un o p’edidi na mọ,

Bi ‘gbese tilẹ tan,

O nsọ ìfẹ Ẹni t’ o san

Igbese na fún mi.

 

mf  Mo wo mo si rẹrin,

Mo tun wo, mo sọkún,

Ẹri ìfẹ Rẹ sí mi ni,

Ùn o tọju rẹ titi.

 

Ki tun s’edidi mọ,

Ṣugbọn ìrántí ni,

Pe gbogbo igbese mi ni

Emmanueli san. Amin

 

He gave to me a seal

 

  1. He gave to me a seal

Of the great debt I owe

And as He gave, He smiled and said,

”Always, remember Me.”

 

  1. He gave to me a seal

All of my debts He paid

And as He gave, He smiled and said

”Always, remember Me.”

 

  1. I shall treasure the seal

Though, the debt is all paid

The seal told of the love of One

Who paid the debt for me.

 

  1. I looked at it and smiled

Again, I looked and wept

The earnest of His love for me

I’ll ever treasure it

 

  1. It is more than a seal

It is in remembrance

That all the debt of sin was paid

By Lord, Emmanuel. Amen.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *