Yoruba Hymn: Nipa Ifẹ Olugbala Ki y’o sí nkan – Through the Love of God our Saviour

Yoruba Hymn: Nipa Ifẹ Olugbala Ki y’o sí nkan – Through the Love of God our Saviour

Nipa Ifẹ Olugbala Ki y’o sí nkan – Through the Love of God our Saviour

Hymn no.626 of the Christ Apostolic Church Hymn Book

Nipa Ifẹ Olugbala ki y’o sí nkan

Nipa ifẹ Olugbala,
Ki y'o sí nkan
Oju rere Rẹ ki pada
Ki y'o sí nkan,
Ọwọn l'ẹjẹ t'o wowa san;
Pipe ledidi or'or'ọfẹ,
Agbara l'ọwọ t'o gba ni
Ko le si nkan.

Bi a wa ninu ipọnju
Ki y'o sí nkan,
Igbala kikun ni tiwa,
Ki y'o sí nkan;
Igbẹkẹle Ọlọrun dun;
Gbigbe inu Kristi l'ere,
Ẹmi sí nsọ wa di mimọ
Ko le sí nkan.

Ọjọ ọla yíò dara,
Ki y'o sí nkan,
'Gbagbọ le kọrin n'nu 'pọnju
Ki y'o sí nkan;
Agbẹkẹle 'fẹ baba wa;
Jesu nfun wa l'ohun gbogbo
Ni yiye tabi ni kiku,
Ko le sí nkan.

Through the love of God our Saviour

Through the love of God our Saviour,
All will be well;
Free and changeless is His favour,
All, all is well:
Precious is the blood that healed us;
Perfect is the grace that sealed us;
Strong the hand stretched
forth to shield us;
All must be well.

Though we pass through tribulation,
All will be well;
Christ hath purchased full salvation,
All, all is well:
Happy still in God confiding;
Fruitful, if in Christ abiding;
Holy, through the Spirit's guiding;
All must be well.

We expect a bright tomorrow;
All will be well;
Faith can sing through days of sorrow,
All, all is well:
On our Father's love relying,
Jesus every need supplying,
Then in living or in dying,
All must be well.

Author: Frances R. Havergal

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *