Yoruba Hymn: Asẹgun ati Ajogun ni a jẹ – Conquerors and Overcomers now are we

Yoruba Hymn: Asẹgun ati Ajogun ni a jẹ – Conquerors and Overcomers now are we

Asẹgun ati Ajogun ni a jẹ – Conquerors and Overcomers now are we

 

Bible Reference: 

Romans 8:37 KJV – Nay, in all these things we are more than conquerors through him that loved us.

Romu 8:37 –  Ṣugbọn ninu gbogbo nkan wọnyi awa jù ẹniti o ṣẹgun lọ nipa ẹniti o fẹ wa.

 

Asẹgun ati Ajogun ni a jẹ

Verse 1

Asẹgun ati ajogun ni a jẹ

Nipa ẹjẹ Kristi a ni ìṣẹgun

B’Oluwa jẹ tiwa, a kì yo ṣubu

Ko s’ohun to le bori agbara Rẹ

Asẹgun ni wa, nipa ẹjẹ Jesu

Baba fún wa nì ‘segun, nipa ẹjẹ Jesu;

Ẹni t’a pa felese

Sibẹ, O wa, O njọ́ba;

Awa ju asẹgun lọ

Awa ju asẹgun lọ.

Verse 2

A n; ọ l’orukọ Ọlọrun Israẹli

Lati ṣẹgun ẹsẹ at’aisododo;

K’ise fun wa, ṣugbọn Tirẹ ni ìyìn

Fún ‘gbala at’isegun ati f’ẹjẹ ra.

Asẹgun ni wa, nipa ẹjẹ Jesu

Baba fún wa nì ‘segun, nipa ẹjẹ Jesu;

Ẹni t’a pa felese

Sibẹ, O wa, O njọ́ba;

Awa ju asẹgun lọ

Awa ju asẹgun lọ.

Verse 3

Ẹni t’Oba sì ìṣẹgun li ao fi fún

Lati jẹ manna to t’ọ́run wa nihin

L’ọ́run yo sí gbe imọ́ pe asẹgun,

Yo wọ sọ́ funfun, yo sí dade wura.

Asẹgun ni wa, nipa ẹjẹ Jesu

Baba fún wa nì ‘segun, nipa ẹjẹ Jesu;

Ẹni t’a pa felese

Sibẹ, O wa, O njọ́ba;

Awa ju asẹgun lọ

Awa ju asẹgun lọ.

Conquerors and overcomers now are we

Conquerors and overcomers now are we,

Thro’ the precious blood of Christ we’ve victory

If the Lord be for us we can never fail,

Nothing ‘gainst His mighty power can e’er prevail.

Chorus

Conquerors are we, thr’o the blood of Jesus

God will give us victory, thro’ the blood of Jesus

Through the Lamb for sinners slain,

Yet who lives and reigns again,

More than conquerors are we,

More than conquerors are we.

Verse 2

In the name of Israel’s God we’ll onward press,

Overcoming sin and all unrighteousness;

Not to us but unto Him the praise shall be,

For salvation and for blood bought victory.

Chorus

Conquerors are we, thr’o the blood of Jesus

God will give us victory, thro’ the blood of Jesus

Through the Lamb for sinners slain,

Yet who lives and reigns again,

More than conquerors are we,

More than conquerors are we.

Verse 3

Unto Him that overcometh shall be given,

Here to eat of hidden manna sent from Heaven,

Over yonder He the victors palm shall bear,

And a robe of white, and golden crown shall wear.

Chorus

Conquerors are we, thr’o the blood of Jesus

God will give us victory, thro’ the blood of Jesus

Through the Lamb for sinners slain,

Yet who lives and reigns again,

More than conquerors are we,

More than conquerors are we.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *