Yoruba Hymn: Jesu Fẹ Mi, Mo Mọ Bẹ – Jesus Loves Me! This I know

Yoruba Hymn: Jesu Fẹ Mi, Mo Mọ Bẹ – Jesus Loves Me! This I know

Hymn: Jesu Fẹ Mi, Mo Mọ Bẹ – Jesus Loves Me! This I know 

Bible Reference: 

Mark 10:16 (KJV)  And he took them up in his arms, put his hands upon them, and blessed them.

Marku 10:16 – O si gbé wọn si apa rẹ̀, o gbé ọwọ́ rẹ̀ le wọn, o si sure fun wọn.

Jesu Fẹ Mi, Mo Mọ Bẹ

Jesu fẹ mi, mo mọ bẹ,
Bibeli l’o sọ fun mi;
Tire l’ awon ọmọde,
Nwọn ko lagbara, On ni.
Jesu fẹ mi, Ẹn’ t’o ku
Lati ṣi orun silẹ;
Yio wẹ ẹsẹ mi nu:
Jẹ ki ọmọ Rẹ wọlé.
Jesu fẹ mi sibẹ si,
Bi emi tilẹ s’aisan
Lor’ akete aisan mi,
Yio t’ itẹ Rẹ wa sọ mi.
Jesu fẹ mi, y’o duro
Ti mi ni gbogb’ ọna mi,
’Gba mba f’aiye yi silẹ,
Y’o mu mi re ’le ọrun. Amin.

Jesus Loves Me! This I know

Jesus loves me! This I know,
For the Bible tells me so;
Little ones to Him belong,
They are weak but He is strong.
Jesus loves me! He who died,
Heaven's gate to open wide;
He will wash away my sin,
Let His little child come in.
Jesus loves me! loves me still,
When I'm very weak and ill;
From His shining throne on high,
Comes to watch me where I lie.
Jesus loves me! He will stay,
Close beside me all the way;
He's prepared a home for me,
And some day His face I'll see. Amen

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *