Yoruba Hymn: Isun kan wa t’o kun f’ẹjẹ – There is a fountain filled with blood
Isun kan wa t’o kun f’ẹjẹ – There is a fountain filled with blood
Bible Reference:
Zechariah 13:1 KJV – In that day there shall be a fountain opened to the house of David and to the inhabitants of Jerusalem for sin and for uncleanness.
Sekariah 13 :1 – 1 LI ọjọ na isun kan yio ṣi silẹ fun ile Dafidi ati fun awọn ara Jerusalemu, fun ẹ̀ṣẹ ati fun ìwa aimọ́.
Isun kan wa t’o kun f’ẹjẹ
VERSE 1
Isun kan wa t’o kun f’ẹjẹ,
To ti ‘ha Jesu yọ;
Ẹlẹsẹ mokun ninu rẹ,
O bọ ninu ẹbi.
VERSE 2
‘Gba mo f’ ìgbàgbọ́ r’ isun na,
Ti nsan fun ẹjẹ Rẹ,
Irapada d’ orin fun mi,
Ti ùn o ma kọ titi.
VERSE 3
Orin t’o dun ju eyi lọ,
Li emi o ma kọ:
‘Gbat’ akololo ahọn yi
Ba dake ni iboji.
VERSE 4
Mo gbagbo p’ O pese fun mi
Bi mo tilẹ s’a aiye,
Ẹbùn ọfẹ t’ a f’ ẹjẹ ra,
Ati duru wura.
VERSE 5
Duru t’ a tọw’ Olorun ṣe,
Ti ko ni bajẹ lai;
Ti ao ma fi yin Baba wa,
Orúkọ Rẹ nikan. Amin.
There is a fountain filled with blood
VERSE 1
There is a fountain filled with blood
Drawn from Emmanuel’s veins;
And sinners plunged beneath that flood
Lose all their guilty stains.
VERSE 2
E’er since, by faith, I saw the stream
Thy flowing wounds supply,
Redeeming love has been my theme,
And shall be till I die.
VERSE 3
Then in a nobler, sweeter song,
I’ll sing Thy power to save,
When this poor lisping, stammering tongue
Lies silent in the grave.
VERSE 4
Lord, I believe Thou hast prepared,
Unworthy though I be,
For me a blood bought free reward,
A golden harp for me!
VERSE 5
’Tis strung and tuned for endless years,
And formed by power divine,
To sound in God the Father’s ears
No other name but Thine, Amen.