Yoruba Hymn: Ileri mimọ, Jesu n’temi – Blessed assurance, Jesus is mine

Hymn: Ileri mimọ, Jesu n’temi – Blessed assurance, Jesus is mine
Bible Reference:
1 Peter 1:8 NKJV – whom having not seen you love. Though now you do not see Him, yet believing, you rejoice with joy inexpressible and full of glory,
01 Peteru 01:08 – Ẹniti ẹnyin fẹ lairi, ẹniti ẹnyin gbagbọ, bi o tilẹ ṣepe ẹ kò ri i nisisiyi, ẹnyin si nyọ ayọ̀ ti a kò le fi ẹnu ṣo, ti o si kun fun ogo
Ileri mimọ, Jesu n’temi
Ileri mimọ, Jesu n'temi; Adun ogo nla, ọrun didan; Ajogun igbala, ọmọ Ọlọrun; Ọmọ Ẹmi ta fi ẹjẹ wẹ.
Refrain: Eyi nitan mi, atorin mi Ki n ma yin Jesu lọjọ gbogbo, Eyi nitan mi, atorin mi- Ki n ma yin Jesu lọjọ gbogbo.
Ijewo mimọ, ayọ didun Iran ayọ nla 'be niwaju mi Angel' sọkalẹ lati ọrun Pẹlu iyin, syọ at'ifẹ
Ijewo mimọ, mo r'isinmi Ninu Oluwa, mo r'ibukun Mo duro, mo n sọnà mo n woke Mo kun fun ore at'ifẹ Rẹ
Come to me, Lord, when first I wake
Blessed assurance, Jesus is mine; Oh, what a foretaste of glory divine! Heir of salvation, purchase of God, Born of His Spirit, washed in His blood.
Refrain: This is my story, this is my song, Praising my Savior all the day long. This is my story, this is my song, Praising my Savior all the day long.
Perfect submission, perfect delight, Visions of rapture now burst on my sight; Angels descending, bring from above Echoes of mercy, whispers of love.
Perfect submission, all is at rest, I in my Savior am happy and blest; Watching and waiting, looking above, Filled with His goodness, lost in His love.