Yoruba Hymn: Si Ọ Olutunu Ọrun – To Thee O Comforter Divine

Yoruba Hymn: Si Ọ Olutunu Ọrun – To Thee O Comforter Divine

Si Ọ Olutunu Ọrun – To thee, O Comforter divine

Bible Reference: 

Psalms 145:5 –  I will meditate on the glorious splendor of Your majesty, And on Your wondrous works. 

Orin Dafidi 145:5 – Emi o sọ̀rọ iyìn ọla-nla rẹ ti o logo, ati ti iṣẹ iyanu rẹ.

Si Ọ Olutunu Ọrun

Si Ọ Olutunu Ọrun
Fún ore at'agbara Rẹ
A nkọ, Aleluya.

Si Ọ, ìfẹ ẹni t'O wa
Ninu Majẹmu Ọlọrun
A nkọ, Aleluya.

Si Ọ, agbara Ẹni ti
O nwẹ ni mọ, t'o nwo ni san
A nkọ, Aleluya.

Si Ọ, Olukọ at'ọrẹ,
Amọna wa totọ d'opin,
A nkọ, Aleluya.

Si Ọ, Ẹnití Kristi ran,
Ade on gbogbo ẹbun Rẹ,
A nkọ, Aleluya.

To Thee, O Comforter Divine

To thee, O Comforter divine,
for all thy grace and power benign,
sing we alleluia!

To thee, whose faithful love had place
in God's great covenant of grace,
sing we alleluia!

To thee, whose faithful power doth heal,
enlighten, sanctify, and seal,
sing we alleluia!

To thee, by Jesus Christ sent down,
of all his gifts the sum and crown,
sing we alleluia!

Author: Frances R. Havergal

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *