Yoruba Hymn: Pa mi mo ‘nu ife Re – Jesus keep me in your love

Yoruba Hymn: Pa mi mo ‘nu ife Re – Jesus keep me in your love

RCCG Hymn: Hymn 444: Pa mi mo ‘nu ife Re – Jesus keep me in your love


Bible Reference: 

John 3:16 NKJV – For God so loved the world that He gave His only begotten Son, that whoever believes in Him should not perish but have everlasting life.

Johannu 03:16 –  Nitori Ọlọrun fẹ araiye tobẹ̃ gẹ, ti o fi Ọmọ bíbi rẹ̀ kanṣoṣo funni, ki ẹnikẹni ti o ba gbà a gbọ́ má bà ṣegbé, ṣugbọn ki o le ni ìye ainipẹkun.

Pa mi mo ‘nu ife Re

Verse 1

Pa mi mọ ‘nu ìfẹ Rẹ 
Kin ma gbe bẹ titi
F’ ẹmi mimọ Rẹ kun mi,
Kin ma sin Ọ titi

Chorus
‘Nu ‘fẹ Rẹ, ‘nu ‘fẹ Rẹ 
Kin ma gbe bẹ titi
Pa mi mọ ‘nu ìfẹ Rẹ 
Kin ma gbe bẹ titi

Verse 2

Pa mi mọ ‘nu ìfẹ Rẹ 
Bi ẹbọ alaaye
Ki nfi Mimọ se ‘gbõran
Kin ma sin Ọ titi.

Verse 3

Pa mi mọ ‘nu ìfẹ Rẹ,
Ki nfẹ Ọ ju ‘ye lọ,
Kin jẹ olotọ d’ opin,
K nma sin Ọ titi.

Verse 4

Pa mi mọ ‘nu ìfẹ Rẹ,
Ki’ ebei Rẹ gbe ọkan mi,
K’ ododo je ongbẹ mi
Kin ma sin Ọ titi
 

Jesus keep me in your love

Verse 1

Jesus keep me in your love
There do dwell forever. 
Fill me with your own spirit
There to serve you ever.

Chorus:                         
In your love, in your love 
There to dwell forever
Jesus keep me in your love,
There to dwell forever

Verse 2

Jesus keep me in your love
A living sacrifice,
Holy, willing, obedient,  
There to serve you ever.

Verse 3

Jesus keep me in your love,
Loving you more than life, 
Faithful to Thee to the end, 
There to serve you ever.

Verse 4

Jesus keep me in your love 
Hungering for you only
Thirsting for your righteousness
There to serve you ever.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *