Yoruba Hymn: Oluwa, emi sa ti gbohun Re – I am Thine, O Lord; I have heard Thy voice

Yoruba Hymn: Oluwa, emi sa ti gbohun Re – I am Thine, O Lord; I have heard Thy voice

Hymn: Oluwa, emi sa ti gbohun Re – I am Thine, O Lord; I have heard Thy voice

Bible Reference: 

Song of Solomon 1:4 NKJV– Draw me away! We will run after you. 

Orin Solomon –  Fà mi, awa o sare tọ̀ ọ

Oluwa, emi sa ti gbohun Re

Oluwa, emi sa ti gbohun Rẹ,
O nsọ ìfẹ Rẹ si mi:
Ṣugbọn mo fẹ nde l’apa igbagbọ,
Kin le tubọ sunmọ Ọ.

Fa mi mọra, mọra Oluwa,
Sib’ agbelebu t’O ku,
Fa mi mọra, mọra, mora, Oluwa,
Sib’ ẹjẹ Rẹ t’o niye.

Ya mi si mimọ fun iṣẹ Tirẹ,
Nipa ore- ọfẹ Rẹ:
Je ki nfi ọkan igbagbọ w’oke,
K’ ìfẹ mi sí jẹ Tirẹ.
A! ayo mimọ ti wakati kan,
Ti mo lo nib’ itẹ Rẹ,
’Gba mo gbadura si Ọ Ọlọrun,
Ti a sọrọ bi ọrẹ;
Ijinlẹ ifẹ mbẹ ti nko le mọ,
Titi un o kọja odo;
Ayọ giga ti emi ko le sọ,
Titi ùn o fi de ’simi. Amin

I am Thine, O Lord; I have heard Thy voice

I am Thine, O Lord; I have heard Thy voice,
And it told Thy love to me;
But I long to rise in the arms of faith,
And be closer drawn to Thee.

Draw me nearer, nearer, Blessed Lord,
To the Cross where Thou hast died;
Draw me nearer, nearer, nearer, Blessed Lord,
To Thy precious, bleeding side.

Consecrate me now to Thy service, Lord,
By the pow’r of grace divine;
Let my soul look up with a steadfast hope,
And my will be lost in Thine.
Oh! The pure delight of a single hour
That before Thy throne I spend,
When I kneel in prayer, and with Thee, my God,
I commune as friend with friend
There are depths of love that I can not know,
Till I cross the narrow sea;
There are heights of joy that I cannot reach
Till I rest in peace with thee.

Draw me nearer, nearer, Blessed Lord,
To the Cross where Thou hast died;
Draw me nearer, nearer, nearer, Blessed Lord,
To Thy precious, bleeding side.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *