Yoruba Hymn: Ọlọrun mi gbati mo f’iyanu wo – Oh Lord my God when I in awesome wonder
Christ Apostolic Hymn: Ọlọrun mi gbati mo f’iyanu wo – Oh Lord my God when I in awesome wonder
Bible Reference:
Acts 4:24 NKJV – So when they heard that, they raised their voice to God with one accord and said: “Lord, You are God, who made heaven and earth and the sea, and all that is in them
Ise Awọn Aposteli 04:24 – Nigbati nwọn si gbọ́, nwọn fi ọkàn kan gbé ohùn wọn soke si Ọlọrun nwọn si wipe, Oluwa, ìwọ ti o da ọrun on aiye, ati okun, ati ohun gbogbo ti mbẹ ninu wọn:
Ọlọrun mi gbati mo f’iyanu wo
Verse 1
Ọlọrun mi gbati mo f’iyanu wo Gbogbo Aye t'ó ti f'ọwọ Rẹ da Mo ri ‘rawo mo gb’ohun aara ti nsan Agbara Rẹ hàn ni gbogbo aye Ọkan mi nkọrin s'Olugbala mi Agbara Rẹ ti tobi to Ọkan mi nkọrin s'Olugbala mi Agbara Rẹ ti tobi to
Verse 2
Pẹlú 'yanu mo wo 'ṣẹ Rẹ l'aginju Ẹyẹ nkọrin didun lori igi Mo wo ilẹ lat'ori oke gíga Mo r'agbara odo at'afẹfẹ
Verse 3
Gbati mo ro b'Iwọ ti fi Ọmọ Rẹ Silẹ lati ku, ko tilẹ ye mi L'ori agbelebu l'oru ẹsẹ mi Ẹjẹ Rẹ lo ti ki ẹsẹ mi lọ
Verse 4
‘Gbati Jesu ba de n'nu ọla nla Rẹ Lati pe mi ayọ mi yo ti to Gbana ni 'rẹlẹ un o wolẹ lati sìn Un o wipe Ọlọrun ti tobi to Ọkan mi nkọrin s'Olugbala mi Agbara Rẹ ti tobi to Ọkan mi nkọrin s'Olugbala mi Agbara Rẹ ti tobi to. Amin
Oh Lord my God when I in awesome wonder
Verse 1
Oh Lord my God when I in awesome wonder Consider all the works thy hands has made I see the stars I hear the rolling thunder That pass throughout the universe display Then sings my soul my saviour unto thee How great Thou art, how great Thou art! Then sings my soul, my Saviour God, to Thee, How great Thou art, how great Thou art!
Verse 2
When through the woods and forest glades I wander and hear the birds sing sweetly in the trees; when I look down from lofty mountain grandeur, and hear the brook, and feel he gentle breeze;
Verse 3
And when I think that God his son not sparing, Sent him to die – I scarce can take it in, That on the cross my burden gladly bearing, He bled and died to take away my sin:
Verse 4
When Christ shall come with shout of acclamation And take me home- what joy shall fill my heart! Then I shall bow in humble adoration And there proclaim, my God, how great thou art! Then sings my soul my saviour unto thee How great Thou art, how great Thou art! Then sings my soul, my Saviour God, to Thee, How great Thou art, how great Thou art!