Yoruba Hymn: Ojo nla l’ojo ti mo yan – Oh happy day

Yoruba Hymn: Ojo nla l’ojo ti mo yan – Oh happy day

Ojo nla l’ojo ti mo yan – Oh happy day

Hymn no.869 of the Christ Apostolic Church Yoruba Hymn Book

 

Bible Reference: 

Proverbs 16:20b NLT – those who trust the Lord will be joyful.

 

Owe 16:20b –  ẹniti o si gbẹkẹ le Oluwa, ibukún ni fun u.

 

Ojo nla l’ojo ti mo yan

 

Verse 1

 

Ọjọ nla l’ọjọ ti mo yan

Olugbala l’ Ọlọrun mi:

O yẹ ki ọkan mi ma yọ,

K’o sir o ihin na kalẹ.

 

Ọjọ nla l’ọjọ na!

Ti Jesu wẹ ẹsẹ mi nu;

O kọ mi ki nma gbadura,

Ki nma ṣọra, ki nsi ma yọ.

Ọjọ nla l’ọjọ na!

Ti Jesu wẹ ẹsẹ mi nu.

 

Verse 2

 

Iṣẹ Igbala pari na,

Mo di t’ Oluwa mi loni;

On l’o pe mi, ti mo si jẹ,

Mo f’ayọ jipe mimọ na.

 

Verse 3

 

Ẹjẹ mimọ yi ni mo jẹ

F’eni to yẹ lati fẹràn;

Jẹ k’ọrin didun kun ‘le Rẹ,

Nigba mo ba nlọ sin níbẹ.

 

Verse 4

 

Simi, aiduro ọkan mi,

Simi le Jesu Oluwa;

Tani jẹ wipe aiye dun

Ju ọdọ awon Angeli?

 

Verse 5

 

‘Wọ ọrun t’ó ngbo ẹjẹ mi;

Y’o ma tun gbọ lojojumọ

Tit’ọjọ t’ẹmi mi y’o pin

Ni ùn o ma m’ẹjẹ mí na ṣẹ

 

Oh happy day

 

  1. Oh happy day, that fixed my choice

On Thee, my Savior and my God!

Well may this glowing heart rejoice,

And tell its raptures all abroad.

 

Happy day, happy day, when Jesus washed my sins away!

He taught me how to watch and pray, and live rejoicing every day

Happy day, happy day, when Jesus washed my sins away.

 

  1. O happy bond, that seals my vows

To Him Who merits all my love!

Let cheerful anthems fill His house,

While to that sacred shrine I move.

 

  1. ’Tis done: the great transaction’s done!

I am the Lord’s and He is mine;

He drew me, and I followed on;

Charmed to confess the voice divine.

 

  1. Now rest, my long divided heart,

Fixed on this blissful center, rest.

Here have I found a nobler part;

Here heavenly pleasures fill my breast.

 

  1. High heaven, that heard the solemn vow,

That vow renewed shall daily hear,

Till in life’s latest hour I bow

And bless in death a bond so dear.

Amen.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *