Yoruba Hymn: Mo f’aye at’ife mi fun – My life, my love I give to Thee

Yoruba Hymn: Mo f’aye at’ife mi fun – My life, my love I give to Thee

CAC Hymn: Hymn 507: Mo f’aye at’ife mi fun – My life, my love I give to Thee

Bible Reference: 

Matthew 19:27 NKJV – Then Peter answered and said to Him, “See, we have left all and followed You. Therefore what shall we have?”

Matteu 19:27 –  Nigbana ni Peteru dahùn, o si wi fun u pe, Wò o, awa ti fi gbogbo rẹ̀ silẹ, awa si ntọ̀ ọ lẹhin; njẹ kili awa o ha ni?

Mo f’aye at’ife mi fun

Mo f'aye at'ifẹ mi fun
Ọd'aguntan to ku fun mi;
Jẹ ki n le jẹ olotitọ,
Jesu Ọlọrun mi.

Un o wa f'Ẹmi t'O ku fun mi,
Aye mi yo si dun pupọ;
N o wa f'Ẹmi to ku fun mi,
Jesu Ọlọrun mi.

Mo gbagbọ pe Iwọ n gbani
'Tori 'Wọ ku k'emi le la;
Emi yo si gbekele O,
Jesu Ọlọrun mi.
Iwọ t'O ku ni Kalfari,
Lati sọ mi dominira;
Mo yara mi s'ọtọ fun Ọ,
Jesu Ọlọrun mi.

My life, my love I give to Thee

My life, my love I give to Thee,
Thou Lamb of God who died for me;
O may I ever faithful be,
My Savior and my God!

I’ll live for Him who died for me,
How happy then my life shall be!
I’ll live for Him who died for me,
My Savior and my God!
I’ll live for Him who died for me,
How happy then my life shall be!
I’ll live for Him who died for me,
My Savior and my God!
I now believe Thou dost receive,
For Thou hast died that I might live;
And now henceforth I trust in Thee,
My Savior and my God!

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *