Yoruba Hymn: Ka’bukun rẹ – Count your blessings

Hymn: Ka’bukun rẹ – Count your blessings

Ka-bukun-re-Count-your-blessings-1024x683 Yoruba Hymn: Ka'bukun rẹ - Count your blessings

Bible Reference: Romans 8:18 (NKJV)  For I consider that the sufferings of this present time are not worthy to be compared with the glory which shall be revealed in us. 

Romu 08:18 – Nitori mo ṣíro rẹ̀ pe, ìya igba isisiyi kò yẹ lati fi ṣe akawe ogo ti a o fihàn ninu wa.

Nigbati’gbi aye ba nyi lu ọ (Hymn 828CAC)

Nigbati'gbi aye ba nyi lu ọ,
To si dàbí ẹnipe gbogbo rẹ pin,
Ka ibukun rẹ, ṣírò wọn l'ọkọkan,
Iṣẹ Oluwa yo jẹ 'yanu fún ọ,

Refrain

Ka ‘bukun rẹ, ka won l’ọkọkan,

Ka ‘bukun rẹ, wo isẹ Ọlọrun 

Ka ‘bukun rẹ, ka won l’ọkọkan,

Ka ‘bukun rẹ, wa ri ‘sẹ t’ Ọlọrun ṣe.

Ẹrú aniyan ha nwọ ọkan rẹ l'orun!
Iṣẹ t'a pe ọ sí ha sọrọ fún ọ
Ka 'bukun re,  'yemeji yo sí fo lọ,
Orin ìyìn ni yo si gbẹ'nu rẹ kan,

'Gbat' o ba nwo awọn ọlọrọ ayé,
Ronu ọrọ ti Jesu ti ṣe leri;
Ka ibukun rẹ, owo ko le ra wọn,
Ere rẹ lọrun, ati'le rẹ l' oke

Ninu gbogbo ayidayida aye
Maṣe fòyà, Ọlọrun tobi julọ
Ka ibukun rẹ, awọn Angeli y'o tọ ọ,
Wọn yo sí ran ọ lọwọ titi d'opin. Amin.

When upon life’s billows you are tempest tossed

When upon life’s billows you are tempest tossed,
When you are discouraged, thinking all is lost,
Count your many blessings name them one by one,
And it will surprise you what the Lord hath done.

Refrain:

Count your blessings, name them one by one;

Count your blessings, see what God hath done;

Count your blessings, name them one by one,

And it will surprise you what the Lord hath done.

Are you ever burdened with a load of care?
Does the cross seem heavy you are called to bear?
Count your many blessings, every doubt will fly,
And you will be singing as the days go by.

When you look at others with their lands and gold,
Think that Christ has promised you His wealth untold.
Count your many blessings, money cannot buy
Your reward in heaven, nor your Lord on high.
So amid the conflict, whether great or small,
Do not be discouraged, God is over all;
Count your many blessings, angels will attend,
Help and comfort give you to your journey’s end.

Author: Johnson Oatman, Jr.

Leave a Reply