Yoruba Hymn: Itan iyanu ti fẹ – Wonderful story of love
Itan iyanu ti fẹ! Sọ fún mi lẹẹkan sí – Wonderful story of love! Tell it to me again
Hymn 397 – CHRIST APOSTOLIC CHURCH HYMNAL
Itan iyanu ti fẹ!
Sọ fún mi lẹẹkan sí
Itan iyanu ti ‘fẹ!
Ẹ gbe orin na ga!
Awọn angẹli nròyin Rẹ,
Awọn Olùṣọ sí gbagbọ
Ẹlẹsẹ iwọ ki y’o gbọ
Itan iyanu ti fẹ.
Iyanu! Iyanu! Iyanu!
Itan iyanu ti ‘fẹ
Itan iyanu ti fẹ!
B’iwo tilẹ sako;
Itan iyanu ti fẹ!
Sibẹ o npe loni
Lat’ ori oke Kalfari,
Lati orisun didun nii,
Lati iṣẹdalẹ aye,
Itan iyanu ti fẹ
Iyanu! Iyanu! Iyanu!
Itan iyanu ti ‘fẹ
Itan iyanu ti fẹ!
Jesu ni isinmi
Itan iyanu ti fẹ!
Fún àwọn Olóòótọ
T’ o sun ni ile nla ọrùn,
Pẹl’awọn to ṣaju wa lọ
Wọn nkọ orin ayọ ọrun,
Itan iyanu t’ifẹ
Iyanu! Iyanu! Iyanu!
Itan iyanu ti ‘fẹ.
Amin.
WONDERFUL STORY OF LOVE
Wonderful story of love!
Tell it to me again;
Wonderful story of love!
Wake the immortal strain.
Angels with rapture announce it,
Shepherds with wonder receive it;
Sinner, O won’t you believe it?
Wonderful story of love!
Wonderful! Wonderful!
Wonderful story, Wonderful story of love!
Wonderful story of love!
Though you are far away;
Wonderful story of love!
Still he doth call today.
Calling from Calvary’s mountain,
Down from the crystal bright fountain,
E’en from the dawn of creation;
Wonderful story of love!
Wonderful! Wonderful!
Wonderful story, Wonderful story of love!
Wonderful story of love!
Jesus provides a rest;
Wonderful story of love!
For all the pure and blest;
Rest in those mansions above us,
With those who’ve gone on before us,
Singing the rapturous chorus;
Wonderful story of love!
Wonderful! Wonderful!
Wonderful story, Wonderful story of love!
Author: J. M. Driver
Born: February 10, 1857, Jefferson County, Illinois. Died: June 7, 1918, Chicago, Illinois. Buried: Fort Wayne, Indiana. John Merritte Driver attended Illinois Agricultural College and Boston
University. He was ordained a Methodist Episcopal minister and served in Prairie, Illinois (as of 1880), and at the People’s Church, Chicago, Illinois (1902-07). He co-edited Songs of the Soul in 1885. Source: hymnary.org