Yoruba Hymn: Gbọ ẹda ọrun nkọrin – Hark The Herald Angels sing

Yoruba Hymn: Gbọ ẹda ọrun nkọrin – Hark The Herald Angels sing

Hymn 151: Gbọ ẹda ọrun nkọrin – Hark The Herald Angels sing

Bible Reference: 

Isaiah 9:6 – NKJV – For unto us a Child is born, Unto us a Son is given; And the government will be upon His shoulder. And His name will be called Wonderful, Counselor, Mighty God, Everlasting Father, Prince of Peace. https://www.ferventxtian.com/word-of-the-day-isaiah-9-vs-6-jesus-the-counselor/

Isaiah 9:6 Nitori a bi ọmọ kan fun wa, a fi ọmọkunrin kan fun wa: ijọba yio si wà li ejika rẹ̀: a o si ma pe orukọ rẹ̀ ni Iyanu, Oludamọ̀ran, Ọlọrun Alagbara, Baba Aiyeraiye, Ọmọ-Alade Alafia.

Gbọ ẹda ọrun nkọrin

VERSE 1

Gbọ ẹda ọrun nkọrin,
“Ogo fun Ọba t’ a bi”.
“Alafia laiye yi”
Ọlọrun ba wa laja.
Gbogbo ẹda, nde l'ayọ,
Ẹ gberin, at'oke wa,
Kede pẹl'angẹli pe
A bi Kristi ni Bẹtilẹhẹm'
Gbọ eda ọrun nkọrin,
Ogo fun Ọba t’ a bi.


VERSE 2

Kristi t'a nyìn l'ogo lọrùn,
Kristi Oluwa tití láé,
Ni igbẹyin wo, o dé,
Ọmọ inú wundia!
W'Ọlọrun di eniyan
Ọlọrun di eniyan
O dun mi k'ó b'eeyan gbe
Jesu, imanuẹli wa. 
Gbọ eda ọrun nkọrin,
Ogo fun Ọba t’ a bi.

VERSE 3

Wo, Alade Alafia!
Wo o, orun ododo!
O mu 'mọlẹ iye wa,
'Lera mbẹ li apa rẹ
O bọ 'go rẹ s'apa kan, 
A bi k’ eniyan ma ku;
A bi k’ o gb’ eniyan ro,
A bi k’ o le tun wa bi.
Gbọ eda ọrun nkọrin,
Ogo fun Ọba t’ a bi

VERSE 4

Wa, ireti oril'ede
F'ọkan wa ṣe 'bugbe Rẹ,
Ndé, irú ọmọ 'birin
Ṣẹgun èṣù ninu wa,
Pa àwòrán Rẹ dipo rẹ,
F'aworan Rẹ dipo rẹ,
Adam'keji lat'oke,
Gba wa pada s'ọrẹ Rẹ. Amin. 
Gbọ eda ọrun nkọrin,
Ogo fun Ọba t’ a bi.


Hark The Herald Angels Sing

VERSE 1

Hark! The herald angels sing,
“Glory to the newborn King;
Peace on earth, and mercy mild,
God and sinners reconciled!”
Joyful, all ye nations rise,
Join the triumph of the skies;
With th’angelic host proclaim,
“Christ is born in Bethlehem!”
Hark! the herald angels sing,
“Glory to the newborn King!”



VERSE 2

Christ, by highest Heav’n adored;
Christ the everlasting Lord;
Late in time, behold Him come,
Offspring of a virgin’s womb.
Veiled in flesh the Godhead see;
Hail th’incarnate Deity,
Pleased with us in flesh to dwell,
Jesus our Emmanuel.
Hark! the herald angels sing,
“Glory to the newborn King!”

VERSE 3

Hail the heav’nly Prince of Peace!
Hail the Sun of Righteousness!
Light and life to all He brings,
Ris’n with healing in His wings.
Mild He lays His glory by,
Born that man no more may die.
Born to raise the sons of earth,
Born to give them second birth.
Hark! the herald angels sing,
“Glory to the newborn King!”

VERSE 4

Come, Desire of nations, come,
Fix in us Thy humble home;
Rise, the woman’s conqu’ring Seed,
Bruise in us the serpent’s head.
Now display Thy saving power,
Ruined nature now restore;
Now in mystic union join
Thine to ours, and ours to Thine.
Hark! the herald angels sing,
“Glory to the newborn King!”


Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *