Yoruba Hymn: Gbọ ẹda ọrun nkọrin – HARK! the herald-angels sing
ÌBÍ JÉSÙ: CAC Hymn 151 / CGS Hymn 41: Gbọ ẹda ọrun nkọrin – HARK! the herald-angels sing
Bible Reference:
Isaiah 9:6 NKJV – Isaiah 9:6 NKJV
[6] For unto us a Child is born, Unto us a Son is given; And the government will be upon His shoulder. And His name will be called Wonderful, Counselor, Mighty God, Everlasting Father, Prince of Peace.
Isaiah 2:11 YCB – Isaiah 9:6 YCB
[6] Nítorí a bí ọmọ kan fún wa, a fi ọmọkùnrin kan fún wa, ìjọba yóò sì wà ní èjìká rẹ̀. A ó sì máa pè é ní Ìyanu Olùdámọ̀ràn, Ọlọ́run Alágbára, Baba ayérayé, Ọmọ ọba aládé Àlàáfíà.
Gbọ ẹda ọrun nkọrin
Ẹsẹ 1
Gbọ ẹda ọrun nkọrin,
“Ogo fun Ọba t’ a bi.”
“Alafia laye yi”
Ọlọrun ba wa làja
Gbogbo ẹdá nde l’ ayọ
Dapọ mọ hihó Ọrun
‘W’ alade alafia!
‘Wọ Oorun ododo de.
Chorus
‘W’ alade alafia!
‘Wọ Oorun ododo de.
Ẹsẹ 2
O bọ ‘go Rẹ sapakan,
A bi k’ eniyan má ku,
A bi k’ o gb’ eniyan ró
A bi k’o le tun wa bi,
Wá, ireti eniyan,
Ṣe ile Rẹ ninu wa;
Nde, Iru Ọmọbinrin,
Bori Eṣu ninu wa.
Ẹsẹ 3
Pa aworan Adam’ run,
F’ aworn Rẹ s’ ipò rẹ
Jọọ, ma ṣai f’ Ẹmi Rẹ kún
Ọkàn gbogb’ Onigbagbọ,
“Ogo fun Ọba t’ a bi,”
Jẹ ki gbogbo wa gberin,
“Alafia laye yi,”
Ọlọrun ba wa laja
HARK! the herald-angels sing
Verse 1
HARK! the herald-angels sing,
Glory to the new-born King,
Peace on earth, and mercy mild,
God and sinners reconciled.
Joyful, all ye nations, rise,
Join the triumph of the skies;
With angelic host proclaim,
Christ is born in Bethlehem.
Chorus
Hark! the herald angels sing,
Glory to the new-born King.
Verse 2
Mild He lays His glory by,
Born that man no more may die;
Born to raise the sons of earth,
Born to give them second birth.
Hail the heaven-born Prince of Peace!
Hail the Sun of Righteousness!
Light and life to all He brings,
Risen with healing in His wings.
Verse 3
Come, Desire of nations, come,
Fix in us Thy humble home;
Rise, the woman’s conquering Seed,
Bruise in us the serpent’s head;
Adam’s likeness, Lord, efface;
Stamp Thy image in its place;
Oh to all Thyself impart,
Form’d in each believing heart.
