Yoruba Hymn: Ẹyin Ọba Ògo – Praise the King of Glory

Yoruba Hymn: Ẹyin Ọba Ògo  – Praise the King of Glory

Hymn 68

Ẹyin Ọba Ògo – Praise the King of Glory

Bible Reference: 

Psalms 98:1 NKJV –  Oh, sing to the Lord a new song! For He has done marvelous things;

Orin Dafidi 98:1 – Ẹ kọrin titun si Oluwa; nitoriti o ti ṣe ohun iyanu:

Ẹyin Ọba Ògo Oun ni Ọlọrun

VERSE 1

Ẹyin Ọba ogo, On ni Ọlọrun
Yin I fún'ṣẹ 'yanu ti O fi hàn,
O wá pẹl'awọn ero mimọ l'ọna,
Osi jẹ imọlẹ wọn l'ọsan l'oru

Refrain: 

Ẹyín angẹli didan lu dùru wura,
Ki gbogbo nyin juba t'ẹ nwo oju Rẹ,
Ni gbogbo'jọba Rẹ, b'aye ti nyi lo,
Iṣẹ Rẹ y'o ma yin
Iṣẹ Rẹ y'o ma yin,
Fi ibukun fún Oluwa ọkan mi

VERSE 2

Ẹ yin fún 'rapada, ti gbogbo ọkan,
Ẹ yin fún orisun imularada,
Fún inú rere ati ìtọjú Rẹ
Fún 'daniloju pe O ngbọ adura,

VERSE 3

Ẹ yin fún idanwo, bi okun ìfẹ, 
T'o nso wa pọ mọ awọn ohun ọrun, 
Fún 'gbogbo ti nṣẹgun 'reti ti ki sa, 
Fún ilé Ògo t'O ti pese fún wa. 

Praise the King of Glory, He is God alone

VERSE 1

Praise the King of Glory, He is God alone;
Praise Him for the wonders He to us hath shown;
For His promised presence all the pilgrim way;
For the flaming pillar and the cloud by day.

Refrain:

Praise Him, shining angels, Strike your harps of gold;
All His hosts adore Him, who His face behold;
Through His great dominion, while the ages roll.
All His works shall praise Him,
All His works shall praise Him,
All His works shall praise Him; bless the Lord, my soul!

VERSE 2

Praise Him for redemption, free to every soul;
Praise Him for the Fountain that can make us whole;
For His gifts of kindness and His loving care;
For the blest assurance that He answers prayer.

VERSE 3

Praise Him for the trials sent as cords of love,
Binding us more closely to the things above;
For the faith that conquers; hope, that naught can dim;
For the land where loved ones gather unto Him.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *