Yoruba Hymn: Ẹyin Angẹli l’ọrun ogo – Angels from the Realms of Glory

Hymn 150: Ẹyin Angẹli l’ọrun ogo – Angels from the Realms of Glory

Bible Reference:

Saying, Where is he that is born King of the Jews? for we have seen his star in the east, and are come to worship him. Matthew 2:2 KJVMatteu 2:2 Nwọn mbère wipe, Nibo li ẹniti a bí ti iṣe ọba awọn Ju wà? nitori awa ti ri irawọ rẹ̀ ni ìla-õrùn, awa si wá lati foribalẹ fun u

Ẹyin Angẹli l’ọrun ogo

VERSE 1

Ẹyin angẹl' l’ orun ogo,
To yi gbogbo aiye ka;
Ẹ ti kọrin dida aiye,
Ẹ sọ t’ ibi mesaiah
Ẹ wa jọsin, Ẹ wa jọsin
Fún Kristi Ọba titun

VERSE 2

Ẹyin Oluṣọ - agutan,
Ti nṣọ́ ẹran yin l'oru,
Imanueli wa ti de,
Irawo Ọmọ na ntan;
Ẹ wa jọsin, Ẹ wa jọsin
Fún Kristi Ọba titun

VERSE 3

Amoye, f'ero yin silẹ,
Wo 'ran didan lokeeere!
Wa 'reti nla orilẹ'de,
Ẹ ti ri irawọ Rẹ.
Ẹ wa jọsin, Ẹ wa jọsin
Fún Kristi Ọba titun

VERSE 4

Onigbagbo ti nteriba,
Ni ’beru at’ ireti
L’ ojiji l’ Oluwa o de
Ti yio mu nyin re ’le.
Ẹ wa jọsin, Ẹ wa jọsin
Fún Kristi Ọba titun

VERSE 5

A nwo b'ọm'ọwọ nisi'yi, 
Y'o gba itẹ Baba Rẹ,
Ao ko gbogbo'aye s'ọdọ Rẹ,
Gbogbo ekun yo wolẹ fún.
Ẹ wa jọsin, Ẹ wa jọsin
Fún Kristi Ọba titun. Amin.

Angels from the Realms of Glory

VERSE 1

Angels from the realms of glory,
Wing your flight o'er all the earth;
Ye who sang creation's story,
Now proclaim Messiah's birth:
Come and worship,
Come and worship,
Worship Christ, the newborn King!

VERSE 2

Shepherds, in the fields abiding,
Watching o'er your flocks by night,
God with man is now residing,
Yonder shines the infant Light;
Come and worship,
Come and worship,
Worship Christ, the newborn King!

VERSE 3

Sages, leave your contemplations,
Brighter visions beam afar;
Seek the great desire of nations,
Ye have seen His natal star;
Come and worship,
Come and worship,
Worship Christ, the newborn King!

VERSE 4

Saints before the altar bending,
Watching long in hope and fear,
Suddenly the Lord, descending,
In His temple shall appear:
Come and worship,
Come and worship,
Worship Christ, the newborn King!

VERSE 5

Though an infant now we view Him,
He shall fill His Father's throne
Gather all the nations to Him;
Every knee shall then bow down.
Come and worship,
Come and worship,
Worship Christ, the newborn King!

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *