Yoruba Hymn: Wa Eyin Olooto – O Come, All Ye Faithful
Hymn: Wa Eyin Olooto – O Come, All Ye Faithful
Bible Reference:
Luke 2:15 NLT
When the angels had returned to heaven, the shepherds said to each other, “Let’s go to Bethlehem! Let’s see this thing that has happened, which the Lord has told us about.”
Luk 2:15 YBCV
O si ṣe, nigbati awọn angẹli na pada kuro lọdọ wọn lọ si ọrun, awọn ọkunrin oluṣọ-agutan na ba ara wọn sọ pe, Ẹ jẹ ki a lọ tàra si Betlehemu, ki a le ri ohun ti o ṣẹ, ti Oluwa fihàn fun wa.
Wa Eyin Olooto
Wa ẹyin olootọ!
L’ayọ at’isẹgun,
Wa ka lọ, wa ka lo si Betlehem
Wa kalo wo o
Ọba awọn Angel’
E wa kalọ juba Rẹ
E wa kalọ juba Rẹ
E wa kalọ juba Kristi Oluwa
Olodumare ni
Imọlẹ ododo,
Ko si korira inu wundia
Ọlọrun papa
Ti a bi, t’a ko da!
Angẹli, e kọrin
Korin itoye Rẹ!
Ki gbogbo ẹda ọrun si gberin,
Ogo f'Ọlọrun
L’oke ọrun lọhun!
Nitotọ a wolẹ
F’Ọba t’a bi loni,
Jesu Iwọ li awa nf ogo fun!
‘Wo Ọmọ Baba,
T’o gbe ara wa wọ!
Amin.
O Come, All Ye Faithful
O come, all ye faithful,
Joyful and triumphant!
O come ye, O come ye to Bethlehem;
Come and behold him
Born the King of Angels:
O come, let us adore Him,
O come, let us adore Him,
O come, let us adore Him, Christ the Lord.
God of God,
Light of Light,
Lo, he abhors not the Virgin’s womb;
Very God,
Begotten, not created:
Sing, choirs of angels,
Sing in exultation,
Sing, all ye citizens of Heaven above!
Glory to God
In the highest:
Yea, Lord, we greet thee,
Born this happy morning;
Jesus, to thee be glory given!
Word of the Father,
Now in flesh appearing!