Yoruba Hymn: Otitọ Rẹ tobi – Great is Thy faithfulness

Yoruba Hymn: Otitọ Rẹ tobi – Great is Thy faithfulness

Hymn: Otitọ Rẹ tobi – Great is Thy faithfulness

Bible Reference: 

James 1:17 NKJV – Every good gift and every perfect gift is from above, and comes down from the Father of lights, with whom there is no variation or shadow of turning. 

Jakọbu 1:17 – Gbogbo ẹ̀bun rere ati gbogbo ẹ̀bun pipé lati oke li o ti wá, o si nsọkalẹ lati ọdọ Baba imọlẹ wá, lọdọ Ẹniti kò le si iyipada tabi ojiji àyida.

Otitọ Rẹ tobi, Bab’ Ọlọrun mi

Otitọ Rẹ tobi, Bab' Ọlọrun mi,
Ko si ayidayida lọdọ Rẹ;
'Wọ ko yi pad' anu Rẹ ko kuna ri,
Bi O ti wa, bẹẹni O wa titi.
Refrain:

Otitọ Re tobi, otitọ Rẹ tobi.
Laraarọ anu tuntun ni mo n ri,
Gbogb' ohun mo fe lọwọ Rẹ ti pese,
Otitọ Rẹ tobi púpọ si mi
Igba oru, ọyẹ́, oj' ati 'kore,
Orun, osupa, 'rawọ lọnà wọn 
Dapọ m'ẹda gbogbo ni ijẹri si
Otitọ nla, anu at' ìfẹ́ Rẹ.
'Dariji ẹsẹ, alafia to daju,
'Walaye Rẹ to n 'tunu to n dari;
Agbara fun oni, ireti f' ọla,
Ibukun ainiye si jẹ temi.

Great is Thy faithfulness, O Lord my Father

Great is Thy faithfulness, O Lord my Father, 
There is no shadow of turning with Thee; 
Thou changeth not, Thy compassionate they fail not, 
As Thou hast been, Thou forever wilt be. 
Refrain: 

Great is thy faithfulness/2x
Morning by morning new mercies I see
All I have needed Thy hand hath provided.
Great is thy faithfulness Lord unto me
Summer and winter and springtime and harvest,
Sun moon and stars in their courses above 
Join with all nature in manifold witness,
To Thy great faithfulness mercy and love.
Pardon for sin and a peace that endureth,
Thine own dear presence to cheer and to guide;
Strength for today and bright hope for tomorrow,
Blessings all mine with ten thousand beside.

Author: Thomas O. Chisholm

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *