Yoruba Hymn: Olugbala gbohun mi – Loving Saviour, hear my cry

Yoruba Hymn: Olugbala gbohun mi – Loving Saviour, hear my cry

Olugbala gbohun mi – Loving Saviour, hear my cry

 

Bible Reference:

 Psalms 102:1 NLT – Lord , hear my prayer! Listen to my plea!

Orin Dafidi 102:1GBỌ adura mi, Oluwa, ki o si jẹ ki igbe mi ki o wá sọdọ rẹ.

 

Olugbala gbohun mi

 

Olugbala gbohun mi

Gbohun mi, gbohun mi,

Mo wa sọdọ Rẹ, gba mi,

N’ibi agbelebu.

Èmi sẹ sugbọn ‘Wọ ku,

Iwọ ki, Iwọ ku,

Fi anu Rẹ pa mi mọ,

N’ibi agbelebu.

 

Oluwa, jọ gba mi,

K’ yo bi Ọ ninu mọ

Alabukun gba mi

N’ ibi agbelebu.

 

Bi ngo ba tile ṣegbe,

Ngo bẹbẹ! ngo bẹbẹ!

Iwọ ni ọna iye,

N’ibi agbelebu;

Ore-ọfẹ Rẹ t’a gba,

L’ọfẹ ni! L’ọfẹ ni!

F’oju anu Rẹ wo mi,

N’ibi agbelebu. 

 

Oluwa, jọ gba mi,

K’ yo bi Ọ ninu mọ

Alabukun gba mi

N’ ibi agbelebu.

 

F’ẹjẹ mimọ Rẹ wẹ mí,

Fi wẹ mí, fi wẹ mí;

Ri mi sinu ibu Rẹ,

N’ibi agbelebu,

‘Gbagbọ l’o le fún wa ni

‘Dariji! Dariji!

Mo f’igbagbọ rọ mọ Ọ

N’ibi agbelebu.

 

Oluwa, jọ gba mi,

K’ yo bi Ọ ninu mọ

Alabukun gba mi

N’ ibi agbelebu.

 

Amin

 

  1. Loving Saviour, hear my cry,

Hear my cry, hear my cry;

Trembling to Thine arms I fly:

O save me at the Cross!

I have sinn’d, but Thou hast died,

Thou hast died, Thou hast died;

In Thy mercy let me hide:

O save me at the Cross!

 

Lord Jesus, receive me,

No more would I grieve Thee,

Now, blessed Redeemer,

O save me at the Cross!

 

  1. Tho’ I perish I will pray,

I will pray, I will pray;

Thou of life the Living Way:

O save me at the Cross!

Thou hast said Thy grace is free,

Grace is free, grace is free:

Have compassion, Lord on me:

O save me at the Cross!

Lord Jesus, receive me, etc.

 

  1. Wash me in Thy cleansing blood,

Cleansing blood, cleansing blood;

Plunge me now beneath the flood:

O save me at the Cross!

Only faith will pardon bring,

Pardon bring, pardon bring:

In that faith to Thee I cling:

O save me at the Cross!

 

Amen. 

 

Author: Fanny J. Crosby

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *