Yoruba Hymn: Ojo Ibukún yíò sì rọ – There Shall be Showers of Blessing
Hymn 656: Christ Apostolic Church Hymnal
Yoruba Version of There Shall be Showers of Blessing Hymn – By Daniel W. Whittle
Bible Reference: I will bless my people and their homes around my holy hill. And in the proper season I will send the showers they need. There will be showers of blessing. Ezekiel 34:26 NLT
Emi o si ṣe awọn ati ibi ti o yi oke mi ká ni ibukún; emi o si jẹ ki ojò ki o rọ̀ li akoko rẹ̀, òjo ibukún yio wà. – Esekieli 34:26
“Ojo ibukun y’o sì rọ”
Ìlérí ìfẹ l’eyi
A o ni itura didun
Lat’ọdọ Olugbala
Refrain:
Ojo ibukun
Ojo ibukun l’a nfẹ
Iri anu nsẹ yi wa ka
Ṣugbọn ojo l’antọrọ
“Ojo ibukun y’o sì rọ”
Isọji iyebiye;
L’ori oke on pẹtẹlẹ
Iro ọpọ ojo mbọ.
Refrain
“Ojo ibukun y’o sì rọ”
Rán wọn sí wa, Olúwa;
Fún wa ni itura didun
Wa f’ọla fún ọrọ Rẹ.
Refrain
“Ojo ibukun y’o sì rọ”
Iba jẹ le rọ loni
B’a tinjẹwọ f’Ọlọrun wa
T’a npe orukọ Jesu
Refrain:
Ojo ibukun
Ojo ibukun l’a nfẹ
Iri anu nsẹ yi wa ka
Ṣugbọn ojo l’antọrọ
There shall be showers of blessing:
This is the promise of love;
There shall be seasons refreshing,
Sent from the Savior above.
Refrain:
Showers of blessing,
Showers of blessing we need:
Mercy-drops round us are falling,
But for the showers we plead.
There shall be showers of blessing,
Precious reviving again;
Over the hills and the valleys,
Sound of abundance of rain.
There shall be showers of blessing;
Send them upon us, O Lord;
Grant to us now a refreshing,
Come, and now honor Thy Word.
There shall be showers of blessing:
Oh, that today they might fall,
Now as to God we’re confessing,
Now as on Jesus we call!
Author: Daniel W. Whittle