Yoruba Hymn: Ogo ni f’Oluwa t’o se ohun nla – To God be the Glory

Hymn: Ogo ni f’Oluwa t’o se ohun nla  – To God be the Glory Great things He has Done!

Ogo-ni-fOluwa-to-se-ohun-nla Yoruba Hymn: Ogo ni f'Oluwa t'o se ohun nla - To God be the Glory

Bible Reference: Psalms 29:2 (KJV)  Give unto the LORD the glory due unto his name; worship the LORD in the beauty of holiness.

Orin Dafidi 29:2 – Ẹ fi ogo fun Oluwa, ti o yẹ fun orukọ rẹ̀; ẹ ma sìn Oluwa ninu ẹwà ìwa-mimọ́. 

Ogo ni f’Oluwa t’o se ohun nla

Ogo ni f'Oluwa t'o se ohun nla
Ìfẹ lo mu k'O fun wa ni Ọmọ Rẹ
Eni t'o f' ẹmi re le'lẹ f'ẹsẹ wa
To si Ilẹkùn iye silẹ fun wa.


Chorus: Yin Oluwa, Yin Oluwa

Fiyin fun Oluwa

Yin Oluwa, Yin Oluwa

Ẹ yọ niwaju Rẹ

K’a tọ Baba wa lọ l’oruko Jesu,

Jẹ k’a jọ f’ogo fun Òníṣẹ-yanu

Irapada kikun ti ẹjẹ Rẹ ra
F'ẹnikẹni t'o gba ileri Rẹ gbọ
Ẹnit'o buruju b'oba le gbagbọ́
Lojukanna yo ri idariji gba
O s'ohun nla fun wa, o da wa l'ọla
Ayọ wa di kikun ninu Ọmọ Rẹ,
Ogo ati ẹwà irapada yi,
Y'o ya wa lẹnu 'gbata ba ri Jesu.

To God be the Glory Great things He has Done!

To God be the glory great things He has done!
So loved He the world that He gave us His Son
Who yielded His life an atonement for sin
And opened the life gate that all may go in.

Praise the Lord! Praise the Lord!

Let the earth hear His voice

Praise the Lord! Praise the Lord!

Let the people rejoice

O come to the father through Jesus the Son

And give Him the glory, great things he has done.

O perfect redemption, the purchase of blood,
To every believer the promise of God!
The vilest offender who truly believes
That moment from Jesus a pardon receives.
Great things, He has taught us great things He has done
And great our rejoicing through Jesus the Son
But purer, and higher and greater will be
Our wonder, our rapture, when Jesus we see

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *