Yoruba Hymn: Odun idasile ti de – The year of jubilee is come

Yoruba Hymn: Odun idasile ti de – The year of jubilee is come

Hymn: E fun’pe na kikan – Blow ye the trumpet, blow! 

(Odun idasile ti de – The year of jubilee is come)

Bible Reference: 

Isaiah 61:1 NKJV – The Spirit of the Lord GOD is upon Me, Because the LORD has anointed Me To preach good tidings to the poor; He has sent Me to heal the brokenhearted, To proclaim liberty to the captives, And the opening of the prison to those who are bound; 

Isaiah 61:1 – ẸMI Oluwa Jehofah mbẹ lara mi: nitori o ti fi ami ororo yàn mi lati wãsu ihin-rere fun awọn òtoṣi; o ti rán mi lati ṣe awotán awọn onirobinujẹ ọkàn, lati kede idasilẹ fun awọn igbekùn, ati iṣisilẹ tubu fun awọn ondè.

E FUN’PE NA KIKAN

E fun'pe na kikan,
Ipe ihinrere
K' o dun jake jado
L' eti gbogbo ẹda;

Odun idasile ti de;

Pada elese, e pada.

Jesu Alufa wa
Ti ṣ'etu Ladele;
Alarẹ, ẹ simi,
Aṣọfọ ẹjẹ Rẹ
Fun 'pe t' Odagutan
T' a ti pa ṣ' etutu;
Je ki agbaiye mọ
Agbara ẹjẹ Re.       
Ẹyin ẹru ẹsẹ
Ẹ sọ 'ra yin d' ọmọ
Lọwọ Kristi Jesu
Ẹ gba ominira yin.  
Gbọ 'pe ìhìnrere
Ìhìn ore-ọfẹ
Agba yin lọw'oye,
Ẹ wa 'waju Jesu. Amin

BLOW YE THE TRUMPET, BLOW!

Blow ye the trumpet, blow!
The gladly solemn sound
Let all the nations know,
To earth’s remotest bound:

Refrain

The year of jubilee is come!

The year of jubilee is come!

Return, ye ransomed sinners, home.

Jesus, our great high priest,
Hath full atonement made,
Ye weary spirits, rest;
Ye mournful souls, be glad:

Extol the Lamb of God,
The sin atoning Lamb;
Redemption by His blood
Throughout the lands proclaim:

Ye slaves of sin and hell,
Your liberty receive,
And safe in Jesus dwell,
And blest in Jesus live:

The Gospel trumpet hear,
The news of heavenly grace;
And saved from earth, appear
Before your Savior’s face:

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *