Yoruba Hymn: Mo ti ni Jesu l’ọrẹ, O j’ohun gbogbo fún mi – I have found a friend in Jesus

Yoruba Hymn: Mo ti ni Jesu l’ọrẹ, O j’ohun gbogbo fún mi – I have found a friend in Jesus

Mo ti ni Jesu l’ọrẹ, O j’ohun gbogbo fún mi

Hymn no.874 of the Christ Apostolic Church Hymn Book

English version of “I have found a friend in Jesus- He’s ev’rything to me,

 

Bible reference:  Song of Solomon 2:1 NKJV I am the rose of Sharon, And the lily of the valleys.

 

Orin Solomoni 2:1 EMI ni itanná eweko Ṣaroni, ati itanná lili awọn afonifoji.

 

Verse 1

 

Mo ti ni Jesu l’ọrẹ, O j’ohun gbogbo fún mi;

On nikan l’arẹwa ti Ọkan mi fẹ

On n’tanna ipado, On no Ẹnikan na

T’o le wẹ mí kúrò ninu ẹsẹ mi.

 

Olutunu mi l’Ojẹ n’nu gbogbo wàhálà

On ni ki nk’aniyan mi l’Oun lori

On ni itanna ipado, irawọ owurọ

On nikan l’arẹwa ti ọkan mi fẹ

 

Verse 2

 

O gbe gbogbo ‘banujẹ at’irora mi ru,

O j’odi agbara mi n’igba ‘danwo

‘Tori Rẹ mo k’ohun gbogbo ti mo ti fẹ sílẹ,

O sí f’agbara rẹ gbé ọkàn mi ro

 

Bí ayé  tilẹ̀ kọ mi, ti Satani dàn mi wo,

Jesu yo mu mi d’opin irin mi;

On ni itanna ipado, irawọ owurọ

On nikan l’arẹwa ti ọkan mi fẹ

 

Verse 3

 

On ki y’o fi mi silẹ, bẹ k’yo kọ mi Nihin

Niwọn ti nba fi ‘gbagbọ p’ofin Rẹ mọ;

Oj’odi’na yi ma ka, nki y’o bẹrùkẹru 

Y’o fi manna Rẹ b’ọkan mi t’ebi npa

 

Gba mbá d’ade n’ikeyin ùn o r’oju ‘bukun Rẹ, 

Ti adun Rẹ o ma san titi láé,

On ni itanna ipado, irawọ Owurọ

On nikan l’arẹwa ti ọkan mi fẹ. 

 

I have found a friend in Jesus- He’s ev’rything to me

 

  1. I have found a friend in Jesus-

He’s ev’rything to me,

He’s the fairest of ten thousand to my soul;

The Lily of the Valley- in Him alone I see

All I need to cleanse and make me fully whole.

 

In sorrow He’s my comfort, in trouble He’s my stay,

He tells me ev’ry care on Him to roll;

He’s the Lily of the Valley, the Bright and Morning Star,

He’s the greatest of ten thousand to my soul.

 

  1. He all my grief has taken and all my sorrows borne,

In temptation He’s my strong and mighty tow’r;

I have all for Him forsaken and all my idols torn

From my heart, and now He keeps me by His pow’r.

 

Though all the world forsake me and Satan tempt me sore,

Through Jesus I shall safely reach the goal;

He’s the Lily of the Valley, the Bright and Morning Star;

He’s the greatest of ten thousand to my soul.

 

3 He will never, never leave me nor yet forsake me here,

While I live by faith and do His blessed will;

A wall of fire about me, I’ve nothing now to fear-

With His manna He my hungry soul shall fill.

 

Then sweeping up to glory I’ll see His blessed face,

Where rivers of delight shall ever roll;

He’s the Lily of the Valley, the Bright and Morning Star;

He’s the greatest of ten thousand to my soul.

 

Author: Charles W. Fry

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *