Yoruba Hymn: Mo fi Gbogbo Rẹ Fun Jesu – All to Jesus I surrender

Yoruba Hymn: Mo fi Gbogbo Rẹ Fun Jesu – All to Jesus I surrender

Hymn: Mo fi gbogbo rẹ fun Jesu – All to Jesus I surrender

Bible Reference: Peter answered him, “We have left everything to follow you! What then will there be for us?” – 

Matthew 19:27 NIV

Nigbana ni Peteru dahùn, o si wi fun u pe, Wò o, awa ti fi gbogbo rẹ̀ silẹ, awa si ntọ̀ ọ lẹhin; njẹ kili awa o ha ni? –  Matteu 19:27

Mo fi gbogbo rẹ fun Jesu

Mo fi gbogbo rẹ fun Jesu,
Patapata l'aiku kan,
Ùn ó ma fẹ, ùn ó si gbẹkẹle,
Ùn ó wa lọdọ Rẹ titi.

CHORUS
Mo fi gbogbo Rẹ (2ce)
Fun Ọ, Olugbala mi, ni
Mo fi wọn silẹ.
Mo fi gbogbo rẹ fun Jesu,
Mo fi 'rẹlǝ wole fun;
Mo fi 'gbadun ayé silẹ;
Gba mi Jesu si gba mi
Mo fi gbogbo rẹ fun Jesu,
Ṣe mi ni Tirẹ nikan
Jẹ kin kun fun Ẹmi mimọ
Ki nmọ pe 'Wọ jẹ temi'
Mo fi gbogbo rẹ fun Jesu
Mo fi ara mi fun ọ
F'ifẹ at'agbara kun mi,
Ki ibukun Rẹ ba le mi.
Mo fi gbogbo rẹ fun Jesu,
Mo mọ p'Ẹmi ba le mi
A! ayọ igbala kikun!
Ogo, ogo, F'okọ Rẹ.

AMIN.

All to Jesus I surrender

All to Jesus I surrender,
All to Him I freely give,
I will ever love and trust Him,
In His presence daily live.


I surrender all,
I surrender all;
All to thee, my blessed saviour,
I surrender all.

All to Jesus I surrender,
Humbly at His feet I bow;
Worldly pleasures all forsaken,
Take me, Jesus, take me now
All to Jesus I surrender,
Lord, I give myself to Thee;
Fill me with Thy love and power,
Let Thy blessings fall on me.
All to Jesus I surrender,
Now I feel the sacred flame,
O the joy of full salvation!
Glory, glory to His name.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *