Yoruba Hymn: Ha! Ẹgbẹ mi, ẹ w’asia – Ho, my comrades, see the signal

Yoruba Hymn: Ha! Ẹgbẹ mi, ẹ w’asia – Ho, my comrades, see the signal

Hymn: Ha! Ẹgbẹ mi, ẹ w’asia – Ho, my comrades, see the signal

Bible Reference:

But hold fast what you have till I come – Revelation 2:25 NKJV

Ṣugbọn eyi ti ẹnyin ni, ẹ di i mu ṣinṣin titi emi o fi de. –  Ifihan 2:25

Ha! Ẹgbẹ mi, ẹ w’asia

Ha! Ẹgbẹ mi, ẹ w’ asia
Bi ti nfẹ lẹlẹ!
Ogun Jesu fẹrẹ dè na, 
A fẹrẹ ṣẹgun!

"D’odi mu, Emi fẹrẹ de"
Bẹni Jesu nwi,
Ran ‘dahun pada s’ ọrun pe,
"Awa o di mu!"
Wo ọpọ ogun ti mbọ wa,
Esu nko wọn bọ;
Awọn alagbara nṣubu,
A fẹ damu tan

D’ odi mu,...
Wo asia Jesu ti nfẹ;
Gbo ohun ipe;
A o ṣẹgun gbogbo ọta
Ni orukọ Rẹ.

D’ odi mu,...
Ogun ngbona girigiri,
Iranwọ wa mbọ;
Balogun wa mbọ wa tete
Ẹgbẹ, tujuka!

D’ odi mu,…


Ho, my comrades, see the signal

Ho, my comrades, see the signal,
waving in the sky!
Reinforcements now appearing,
Victory is nigh.

“Hold the fort, for I am coming,
Jesus signals still;
Wave the answer back to Heaven,
By Thy grace we will.”

See the mighty host advancing,
Satan leading on;
Mighty ones around us falling,
Courage almost gone!
See the glorious banner waving!
Hear the trumpet blow!
In our Leader’s Name we triumph
Over every foe.
Fierce and long the battle rages,
but our help is near;
Onward comes our great Commander,
Cheer, my comrades, cheer!

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *