Yoruba Hymn: Ẹjẹ k’a f’ inu didun – Let us with a gladsome mind

Yoruba Hymn: Ẹjẹ k’a f’ inu didun – Let us with a gladsome mind

Ẹjẹ k’a f’ inu didun – Let us with a gladsome mind

Bible Reference: 

Psalms 136:1 (KJV) – O give thanks unto the LORD; for he is good: for his mercy endureth for ever. 

Orin Dafidi 136:1Ẹ fi ọpẹ fun Oluwa: nitoriti o ṣeun; nitori ti ãnu rẹ̀ duro lailai.

Ẹjẹ k’a f’ inu didun

VERSE 1

Ẹjẹ k’a f’ inu didun,

Yin Oluwa Olore;

Anu Rẹ, O wa titi,

Lododo dajudaju

VERSE 2

On, nipa agbara Rẹ,

F’ imọlẹ s’aiye titun;

Anu Rẹ, o wa titi,

Lododo dajudaju.

VERSE 3

O mbọ gbogb’ ẹda ’laye,

O npese fun aini wọn;

Anu Rẹ, o wa titi,

Lododo dajudaju.

VERSE 4

O bukun ayanfẹ Rẹ,

Li aginju iparun;

Anu Rẹ, o wa titi,

Lododo dajudaju.

VERSE 5

Ẹ jẹ k’a f’ inu didun,

Yin Oluwa Olore;

Anu Rẹ, o wa titi,

Lododo dajudaju. Amin

Let us with a gladsome mind

VERSE 1

Let us with a gladsome mind,

Praise the Lord for He is kind.

For His mercies aye endure,

Ever faithful, ever sure.

VERSE 2

He with all-commanding might

Fill’d the new-made world with light.

For His mercies aye endure,

Ever faithful, ever sure

VERSE 3

All things living He doth feed,

His full hand supplies their need:

For His mercies aye endure,

Ever faithful, ever sure

VERSE 4

He His chosen race did bless

In the wasteful wilderness:

For His mercies aye endure,

Ever faithful, ever sure.

VERSE 5

Let us with a gladsome mind,

Praise the Lord, for He is kind:

For His mercies aye endure,

Ever faithful, ever sure. Amen.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *