Yoruba Hymn: Ẹ wolẹ f’ Ọba, Ologo julọ – O worship the King, All glorious above

Yoruba Hymn: Ẹ wolẹ f’ Ọba, Ologo julọ – O worship the King, All glorious above

CAC Hymn 76: Oluwa, Ọlọrun mi, Iwọ tobi jọjọ

Bible Reference: 

‭‭Psalms 104:1 NKJV‬‬ Bless the Lord, O my soul! O Lord my God, You are very great: You are clothed with honor and majesty,

‭‭Orin Daf 104:1 – FI ibukún fun Oluwa, iwọ ọkàn mi. Oluwa, Ọlọrun mi, iwọ tobi jọjọ: ọlá ati ọla-nla ni iwọ wọ̀ li aṣọ. 

Ẹsẹ 1
Ẹ wolẹ f’ Ọba, Ologo julọ,
Ẹ kọrin ipa Ati ifẹ Rẹ;
Alabò wa ni At’ Ẹni Igbani,
O ngbe ‘nu ogo, Ẹlẹrù ni iyìn
Ẹsẹ 2
Ẹ sọ t’ ipa Rẹ, Ẹ sọ t’ ore Rẹ
‘Mọlẹ l’ aṣọ Rẹ, Gọbì Rẹ Ọrun,
Aara ti nsán ni Kẹkẹ ‘binu Rẹ jẹ:
Ipa ọna Rẹ ni A ko si le mọ.

Ẹsẹ 3
Aye yi pẹlu Ẹkún ‘yanu rẹ
Ọlọrun, agbára Rẹ L’ o dá wọn
O fi idi rẹ mulẹ, Kò si le yi;
O si f’ okun ṣe aṣọ Igunwa Rẹ.
Ẹsẹ 4
Ẹnu ha lè sọ Ti itọju Rẹ?
Ninu afẹfẹ, Ninu imọlẹ?
Itọju Rẹ wa nin’ do Ti o nṣan
O si wa ninu iri Ati ojo.
Ẹsẹ 5
Awa erupẹ, Aw’ alailera,
‘Wọ l’ a gbẹkẹle, O ki o da ni;
Aanu Rẹ rọrun, O si le de opin
Ẹlẹda, Alabo, Olugbala wa.
Ẹsẹ 6
‘Wọ Alagbara, Onifẹ julọ,
B’ awọn angẹli Ti nyin Ọ l’oke
Bẹ l’ awa ẹda Rẹ Niwọn t’ a le ṣe,
A o ma juba Rẹ, A o ma yìn Ọ.

ENGLISH: O worship the King, All glorious above

Verse 1
O worship the King, All glorious above;
O gratefully sing His power and His love;
Our shield and defender, The Ancient of days,
Pavillioned in splendour, And girded with praise.
Verse 2
O tell of His might, O sing of His grace,
Whose robe is the light, whose canopy space;
His chariots of wrath The deep thunder-clouds form,
And dark is His path on the wings of the storm.
Verse 3
The earth with its store of wonders untold,
Almighty! Thy power hath founded of old,
Hath stablished it fast by a changeless decree,
And round it hath cast, Like a mantle, the sea
Verse 4
Thy bountiful care, what tongue can recite?
It breathes in the air; It shines in the light.
It streams from the hills; It descends to the plain,
And sweetly distills in the dew and the rain.
Verse 5
Frail children of dust, and feeble as frail,
In Thee do we trust, nor find Thee to fail;
Thy mercies how tender, how firm to the end,
Our Maker, Defender, Redeemer, and Friend!
Verse 6
O measureless Might! Ineffable Love!
While angels delight to hymn Thee above,
The humbler creation, though feeble their lays,
With true adoration shall lisp to Thy praise!

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *