Yoruba Hymn: B’ orukọ Jesu Ti Dun To – How Sweet The Name of Jesus Sounds
Hymn: B’ orukọ Jesu Ti Dun To – How Sweet The Name of Jesus Sounds
Bible Reference:
Psalms 113:3 – From the rising of the sun to its going down. The LORD’s name is to be praised.
O. Daf 113:3 – Lati ila-õrun titi o fi de ìwọ rẹ̀ orukọ Oluwa ni ki a yìn.
B’ orukọ Jesu Ti Dun To
Ẹsẹ 1
B’ orukọ Jesu ti dun to,
Ògo ni fun orukọ Rẹ;
O tan ‘banujẹ at’ ọgbẹ
Ògo ni fun orúkọ Rẹ;
Chorus
Ògo f’ okọ Rẹ, Ògo f’ okọ Rẹ
Ògo f’ orukọ, Oluwa
Ògo f’ okọ Rẹ, Ògo f’ okọ Rẹ
Ògo f’ orukọ Oluwa.
Ẹsẹ 2
O wo ọkàn t’ o gbọgbẹ san,
Ògo ni fun orúkọ Rẹ,
Ounjẹ ni f’ ọkan t’ ebi npa
Ògo ni fun orukọ Rẹ
Ẹsẹ 3
O tàn aniyàn ẹlẹṣẹ,
Ogo ni fun orúkọ Rẹ;
O fun alarẹ ni ‘simi,
Ogo ni fun orúkọ Rẹ.
Ẹsẹ 4
Njẹ ngo rohin na f’ ẹlẹṣẹ,
Ogo ni fun orúkọ Rẹ;
Pe mo ti ri Olugbala,
Ogo ni fun orúkọ Rẹ.
How sweet the name of Jesus sounds
Verse 1
How sweet the name of Jesus sounds,
Blessed be the name of the Lord;
It soothes his sorrows heals his wounds,
Blessed be the name of the Lord;
Chorus
Blessed be the name, blessed be the name,
Blessed be the name of the Lord;
Blessed be the name, blessed be the name,
Blessed be the name of the Lord;
Verse 2
It makes the wounded spirit whole,
Blessed be the name of the Lord;
‘Tis manna to the hungry soul,
Blessed be the name of the Lord.
Verse 3
It soothes the troubled sinner’s breast,
Blessed be the name of the Lord;
It gives the weary sweetest rest,
Blessed be the name of the Lord.
Verse 4
Then will I tell the sinners round,
Blessed be the name of the Lord;
What a dear Saviour I have found,
Blessed be the name of the Lord.