Yoruba Hymn: Nipa Ifẹ Olugbala – Through the Love of God our Saviour

Nipa Ifẹ Olugbala Ki y’o sí nkan
Hymn no.626 of the Christ Apostolic Church Hymn Book
- Nipa ifẹ Olugbala,
Ki y’o sí nkan,
Oju rere Rẹ ki pada
Ki y’o sí nkan,
Ọwọn l’ẹjẹ t’o wowa san;
Pipe ledidi or’or’ọfẹ,
Agbara l’ọwọ t’o gba ni
Ko le si nkan.
- Bi a wa ninu ipọnju
Ki y’o sí nkan,
Igbala kikun ni tiwa,
Ki y’o sí nka;
Igbẹkẹle Ọlọrun dun;
Gbigbe inu Kristi l’ere,
Ẹmi sí nsọ wa di mimọ
Ko le sí nkan
- Ọjọ ọla yíò dara,
Ki y’o sí nkan,
‘Gbagbọ le kọrin n’nu ‘pọnju
Ki y’o sí nkan;
Agbẹkẹle ‘fẹ baba wa;
Jesu nfun wa l’ohun gbogbo
Ni yiye tabi ni kiku,
Ko le sí nkan.
Amin.
Through the love of God our Saviour
Verse 1
Through the love of God our Saviour,
All will be well;
Free and changeless is His favour,
All, all is well:
Precious is the blood that healed us;
Perfect is the grace that sealed us;
Strong the hand stretched
forth to shield us;
All must be well.
Verse 2
Though we pass through tribulation,
All will be well;
Christ hath purchased full salvation,
All, all is well:
Happy still in God confiding;
Fruitful, if in Christ abiding;
Holy, through the Spirit’s guiding;
All must be well.
Verse 3
We expect a bright tomorrow;
All will be well;
Faith can sing through days of sorrow,
All, all is well:
On our Father’s love relying,
Jesus every need supplying,
Then in living or in dying,
All must be well.