Yoruba Hymn: Gbẹkẹle Onigbagbọ – Trust On, Trust On, Believer
Hymn: Gbẹkẹle Onigbagbọ – Trust on, Trust on, Believer
Bible Reference: Those who trust in the LORD Are like Mount Zion, Which cannot be moved, but abides forever. – Psalms 125:1. NKJV
AWỌN ti o gbẹkẹle Oluwa yio dabi òke Sioni, ti a kò le ṣi ni idi, bikoṣepe o duro lailai.- Orin Dáfídì 125:1
Gbẹkẹle Onigbagbọ
Gbẹkẹle Onigbagbọ Bi'ja na tile pẹ Iwọ ni y'o sa sẹgun, Baba y'o já fún ọ Sa gbẹkẹle B'okunkun tilẹ ṣu Sa gbẹkẹle Ilẹ fẹrẹ mọ na.
Gbẹkẹle l'arin ewu, 'Danwo nla wa n'tosi, L'arin wahala ayé Y'o ma samọna rẹ Sa gbẹkẹle B'okunkun tilẹ ṣu Sa gbẹkẹle Ilẹ fẹrẹ mọ na.
Jesu to lati gba wa, Ọrọ totọ l'O jẹ; Gbẹkẹle, Onigbagbọ Sà gbẹkẹle s'opin. Sa gbẹkẹle B'okunkun tilẹ ṣu Sa gbẹkẹle Ilẹ fẹrẹ mọ na. Amin.
Trust on, Trust on, Believer
Trust on, trust on, believer! Though long the conflict be, Thou yet shall prove victorious; Thy God shall fight for thee. Trust on! Trust on! Though dark the night and drear, Trust on! Trust on! The morning dawn is near.
Trust on! the danger presses, Temptation strong is near, Over life's dangerous rapids He shall thy passage steer. Trust on! Trust on! Though dark the night and drear, Trust on! Trust on! The morning dawn is near.
The Lord is strong to save us, He is a faithful Friend; Trust on, trust on, believer! Oh, trust Him to the end! Trust on! Trust on! Though dark the night and drear, Trust on! Trust on! The morning dawn is near. Amen.