Yoruba Hymn: Ẹyin Ọba Ogo – Praise the King of Glory

Yoruba Hymn: Ẹyin Ọba Ogo – Praise the King of Glory

Ẹyin Ọba Ogo – Praise the King of Glory

Hymn no.68 of the Christ Apostolic Church Hymn Book

 

Bible Reference: 

Psalm 98:1 KJV  – O sing unto the LORD a new song; For he hath done marvellous things: His right hand, and his holy arm, Hath gotten him the victory. 

 

Orin Dafidi 98 :1 – Ẹ kọrin titun si Oluwa; nitoriti o ti ṣe ohun iyanu: ọwọ ọtún rẹ̀, ati apa rẹ̀ mimọ́ li o ti mu igbala wa fun ara rẹ̀.

 

Ẹyin Ọba Ogo

 

VERSE 1

Ẹyin Ọba Ogo, On ni Ọlọrun,

Yin I fún’ṣẹ ‘yanu ti O ti fi han,

Ọ wa pẹl’awọn ero mimọ lọnà,

Osi jẹ imọlẹ wọn l’ọsan l’oru

 

Ẹyin Angẹli didan lu du wura,

Ki gbogbo nyìn juba t’ẹ nwo oju Rẹ

Nigbogbo’jọba Rẹ, b’aye ti nyì lọ,

Iṣẹ Rẹ y’o ma yin,

Iṣẹ Rẹ y’o ma yin,

Fi ibukun fún Oluwa ọkan mi

 

VERSE 2

Ẹyìn fún ‘rapada, ti gbogbo ọkàn

Ẹyin fún orisun imularada,

Fún inú rere ati ìtọjú Rẹ,

Fún ‘daniloju pe O ngbọ adura, 

 

VERSE 3

Ẹyin fún idanwo, bi okun ìfẹ,

T’o nsọ wa pọ mọ awọn ohun ọrun,

fún ‘gbogbo ti nṣẹgun ‘reti ti ki sa

Fún ilé Ogo t’O ti pèse fún wa

 

Praise the King of Glory

 

VERSE 1

Praise the King of Glory, He, is God alone;

praise Him for the wonders He to us hath shown;

For His promised presence all the pilgrim way;

For the flaming pillar and the cloud by day.

 

Praise Him, shining angels, strike your harps of gold;

All His hosts adore Him, who His face behold;

Through His great dominion, while the ages roll.

All His works shall praise Him,

All His works shall praise Him,

All His works shall praise Him;

bless the Lord, my soul!

 

VERSE 2

Praise Him for redemption, free to every soul;

Praise Him for the Fountain that can make us whole;

For His gifts of kindness and His loving care;

For the blest assurance that He answers prayer.

 

VERSE 3

Praise Him for the trials sent as cords of love,

Binding us more closely to the things above;

For the faith that conquers; hope, that naught can dim;

For the land where loved ones gather unto Him.

 

 

Author: Delma B. Reno

Leave a Reply