Yoruba Hymn: Àpáta Ayérayé, Ṣe Ibí Isadi Mi – Rock of Ages Cleft For Me
Àpáta Ayérayé, Ṣe Ibí Isadi Mi – Rock of Ages Cleft For Me
Verse 1
Àpáta ayérayé,
Ṣe ibí isadi mi;
Jẹ kí omi on ẹjẹ,
T’ọsan lati iha Rẹ
Ṣe ìwòsàn f’ẹsẹ mi,
K’o si sọ mi di mímọ
Verse 2
K’ise iṣẹ ọwọ mi
Lo le mu ofin Rẹ ṣe,
B’itara mi ko l’arẹ
T’omije mi nṣàn titi,
Wọn kò tó fún ètùtù
‘Wo nikan lo le gbàla
Verse 3
Ko s’ohun ti mo mu wa,
Mo rọ̀ mọ agbelebu;
Mo wa k’od’asọ̀ bo mi,
Mo nwo Ọ fún iranwọ;
Mo wà sib’orisun ní,
Wẹ mí, Olugbala mí.
Verse 4
‘Gbati ẹmi mi ba pin,
T’iku ba p’oju mi de,
Ti mbá lọ s’aiye aimọ
Ki nri Ọ n’itẹ ‘dajọ́;
Àpáta ayérayé
Se ibí isadi mi.
Rock of Ages, cleft for me,
Verse 1
Rock of Ages, cleft for me,
Let me hide myself in Thee;
Let the water and the blood,
From Thy riven side which flowed,
Be of sin the double cure,
Save me from its guilt and power.
Verse 2
Not the labor of my hands
Can fulfill Thy law’s demands;
Could my zeal no respite know,
Could my tears forever flow,
All could never sin erase,
Thou must save, and save by grace.
Verse 3
Nothing in my hands I bring,
Simply to Thy cross I cling;
Naked, come to Thee for dress,
Helpless, look to Thee for grace:
Foul, I to the fountain fly,
Wash me, Savior, or I die.
Verse 4
While I draw this fleeting breath,
When mine eyes shall close in death,
When I soar to worlds unknown,
See Thee on Thy judgment throne,
Rock of Ages, cleft for me,
Let me hide myself in Thee.